sentence
stringlengths
14
109
root
stringlengths
2
6
root_meaning
stringlengths
3
64
Àwọn Olórò kéde pé orò yóò jáde lọla
ORÒ
A god in Yoruba land
Ọ̀tunla ni àwọn agbagba ilé yóò pín ogún
OGÚN
INHERITANCE
ògèdè jẹ ohun tí a gbọ́dọ̀ se kí a tó wọ ìgbàlẹ̀
Ògèdè
incantation
Gbogbo Abo ni wọ́n ti ni ọkọ tán
Abo
Female
Aya ọmọdé ni ìwà àìgbọràn pọ̀ sí, Egba sì ni ó lè le jáde
ẸGBA
CANE
Àwọn dókítà tí ṣe iṣẹ́ abẹ láti lè kó ọyún inú apá ọkùnrin náà kúrò
ỌYÚN
TUMOR
Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá
KẸKẸ
A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
Àgò ni yóò dé adìẹ gbẹyin
ÀGÒ
THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN
IRỌ̀ pípa ni gbogbo ìgbà, kì í jẹ́ kí a nìyí
IRỌ́
LIE
Mo nílò kí alagbẹdẹ bá mi rọ ẹyá méjì lónìí
ẸYÁ
TEAR
Ìyà Àṣàkẹ́ kì í jẹ́ ọbẹ̀ ọ́yọ́ rárá
Ọ́YỌ́
VEGETABLE
Bàbá Abiodun abà arẹ̀sà kúndùn Ìfà púpọ̀
ÌFÀ
FREEBIE
Èrè ti Ṣọla jẹ lórí ọjà rẹ̀ lo fi ra asọ ọdún
Èrè
Gain/Profit
ìwọ ni o se iku pa ọmọ náà
Ìwọ
You:
Akin se àbúrò rẹ ni osẹ́
Ọsẹ́
injury
Àwọn Obí n ṣeré ní àyíká
Obí
kid/baby
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà bẹ̀rẹ̀ láti kí Ọ̀gá wọn
BẸ̀RẸ̀
BEND
Aró dà sí asọ tuntun ti mo ṣẹṣẹ rà
Aró
Dye
Ṣọla ati Bode nlọ ọjà lọla
Ọjà
market
Ẹsẹ̀ ni ọta ti ba ọdaràn náà
Ọta
Bullet
Ìgbá ti mọ ká ní àná ni mo fí ṣe irú to wa nínú ọbẹ̀ yìí
Ìgbá
locus
Ọwọ́ ni olukọ ti fún ọmọ náà lẹ́gba
Ọwọ́
Hand
Ìyá àgbà so wípé àsán ni a máa jẹ oúnjẹ alẹ́
ÀSÁN
EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT
Ogunleke ń gbìyànjú láti pá àsá abàmì náà
ÀSÁ
EAGLE
ìyàwó burúkú dùn-ún fẹ́, àna burúkú ni o dùn-ún ni
Àna
inlaw
Bá mi dá Ẹ̀kọ wá ní búkà
Ẹ̀kọ
Local food derived from maize
Ẹ̀kọ̀ ni ọkùnrin kọ Obìnrin nílé ọkọ
Ẹ̀KỌ̀
Abandoned
Oyè jagun nílu Feyikogbon da wàhálà silẹ
Jagun
A military title
OLÓRÍ ilé àwọn Talabi ti tẹri gba aṣọ
OLÓRÍ
LEADER
Ìyá mi àti orogún wọn nífẹ̀ẹ́ ara wọn dọba
OROGÚN
RIVAL
Ríru omi ÒKUN bo ọkò ojú omi náà mọlẹ
Òkun
Ocean
itẹ́ ni wọ́n sin àwọn òkú ṣí
Itẹ́
Burial ground
Yíyọ́ Ẹkùn t'ojo kọ́ o dábírà ni
Ẹkùn
Leopard
Bí àgbẹ̀ bá da oko dáadáa yíò rí èrè níbẹ̀
Oko
farm
Ẹ̀kún rọ́bà epo ni mo fẹ́
Ẹ̀kún
Fullness
ORÍ ni kí ẹ ma bọ kí ẹ fi òrìsà sílẹ̀
ORÍ
null
Ọ̀tunla ni ọdún Ògún ni ìlú Ondo
ÒGÚN
god OF THUNDER
Olóyè Ọ̀yọ́ Aláàfin ni bàbá mi
Ọ̀YỌ́
A STATE IN NIGERIA
Ọdẹ fí ỌFÀ pa ọ̀kẹ́rẹ́ ni orí igi
Ọfà
catapult
Ọgbọ́n ọlọgbọ́n ni kìí jẹ kí a pè àgbà ní wéré
Ọgbọ́n
Wisdom
Ṣe ọmọ náà wá sí ilé ìwé,rárá kò wá
Rárá
At all
àyà Ṣọla já nígbà tí o gburó ìbọn
Àyà
Chest
ìlú òkò jẹ́ ọ̀kan lára ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́
Òkò
A town in Oyo state
Òkùn kọni kùn ki onínú má monú
Òkùn
Darkness
Gẹ̀gẹ̀ ti Aduke ni mú kí o burẹ́wà
Gẹ̀gẹ̀
A protuberance on the neck
Àwọn ilé tí o wà ní Àjá ti wọ́n jù
Àjá
A place in Lagos
Apá kan ni ọkùnrin náà ni
Apá
Hand
Ọjọ́ ìsinmi tó ń bọ̀ ni ìsìn ìkẹyìn nínú oṣù yii
ÌSÌN
WORSHIP
Ìpínlẹ̀ Ògùn náà rẹ̀wá ni ìwọ̀nba
ÒGÙN
A STATE IN NIGERIA
Àwọn ìjọba tí ṣe àdéhùn láti san owó òógùn ojú àwọn òṣìṣẹ́
ÒÓGÙN
SWEAT
Pakute tí mo dẹ fún ọ̀ọ́fàn, aláàmù ló mú
ALÁÀMÙ
LIZARD
Àjọ àkọ́kọ́ tí mo dá, ní mo fi ra kẹ̀kẹ́
ÀJỌ
CONTRIBUTION
Mo fẹ́ kí a yọ sí ọ̀daràn náà ni òjijì
ÒJIJÌ
SUDDENLY
Ọ̀wẹ̀ tí mo gbà ní ọdún tí ó kọjá pé mi púpọ̀
Ọ̀wè
A COMPANY SUMMONED TO ASSIST ONE OF THEIR MEMBER IN MANUAL LABOR
ikùn aláboyún naa tóbi púpọ̀
Ikùn
Stomach
Oṣù tí ó ń bọ̀ ni ìyá Ayinla máa jáde nílé opó
OPÓ
WIDOW/WIDOWER
ẹni tí ò ki ni kú ilé ó pà dànù ẹku Abọ̀
Abọ̀
welcome
Igi ọ̀pẹ ẹgbẹ̀rún kan ni a gbìn sí orí ilẹ̀ tuntun náà
Ọ̀PẸ
PALM
Ẹ̀KỌ́ ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ kọ́ ní ogbà àwọn ẹranko
Ẹ̀KỌ́
Knowledge
Ògùn yìí dára fún ojú ṣíṣú
ÒGÙN
MEDICINE
Aràrá ni olùkọ́ ède yorùbá
Ràrá
Dwarf
Ó yẹ kí gbogbo sa ipá láti dènà aburú ọjọ́ iwájú
IPÁ
ABILITY
Òpó náà kò rí Ẹsẹ̀ fi múlẹ̀ dáradára mọ oooo
ÒPÓ
PILLAR
Ọmọ bíbí ìlú ìré ni Akinyemi, ọ̀rẹ́ Taiwo
Ìré
A town in Osun State, Nigeria
Ẹ gbìyànjú láti fi ilẹkun ilé sí pí padé
PADÉ
TO SHUT, TO CLOSE UP
Ọsẹ dúdú ni Adé fi n wẹ̀
Ọsẹ
Soap
Igi Afàrà dára fún ilé kíkàn
Afàrà
Shingle wood
Mo nílò láti kó àwo bí mẹ́ta lọ sí ilé ẹ̀kọ́
ÀWO
PLATE
Osé mẹta ni ó wà ní ilẹ̀ fún nílò ní ọdún yii
OSÉ
A TOOL USED BY SANGO WORSHIPPERS
Ọmọ náà gbá iná mú
Iná
Fire🔥
Ẹ Funmi ni ìṣù ọkà mẹ́jọ péré
ỌKÀ
YORÙBÁ LOCAL FOOD
Bàbá Orisabunmi pa ejò isán ní ńlá kan ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá
ISÁN
A TYPE OF SNAKE (WHICH LIKE SLEEPING)
Àáyá gbọ́n, Ògúngbè gbọ́n
Àáyá
species of monkey
Ní òjijì, òkúta ńlá ré lu ọdẹ náà
ÒJIJÌ
SUDDENLY
Mo fi agbọ̀n kó irè oko wá lé
Agbọ̀n
Basket
ijọ́ tí ènìyàn bá dá ẹ̀jẹ́ kìí mọ̀, àyàfi tí ìṣòro bade
Ẹ̀jẹ́
convenant
Ajá tí yóò sọnù, kìí gbó ìfé ọdẹ
ÌFÉ
WHISTLING
Ẹ rí i dájú pé Irọ̀ ni àwọn ọmọ tí ẹ fẹ́ kó jọ fún ìdíje yìí
IRỌ̀
AGE MATE
Itan mi ti ó tóbi ni kò jẹ́ kí n le sáré dáadáa
ITAN
THIGH
kò dára kí ọmọdé máa wo òjìji ara rẹ̀
ÒJÌJI
SHADOW
Ìlù àti orin jẹ́ ọmọ ìyá kan náà
Ìlù
drum
Agbè bàbá Kọ́lá elẹ́mu tí kún fún ẹmu gidi
AGBÈ
BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER
Ẹ kìlọ̀ fún àwọn ọmọ yín kí wọn má fi Ògún búra èké o
ÒGÚN
god OF THUNDER
A n t'ori Àjà jà,Àjà ní ta lọ njà lẹ́kùnlé òhun
Àjà
Roof
Ìsín ni Ìwọ̀ mi gbé wa si òkè odò
ÌSÍN
SMALL CATFISH
Kí á má parọ́, Ìfà ni ó kó bá Fioye
ÌFÀ
FREEBIE
ỌSÁN tí ó di ìlù náà mu' jẹ́ kí ohùn dún dáadáa
Ọsán
One of the rope used to tie talking drum
Àró pa ẹran ìgbẹ́ bọ̀ l'oko
Àró
Name of person
Adìẹ ìyá àgbà ti n yé ẹyin
Ẹyin
Egg
Ibi tí Ìfẹ́ bá wà, ohun gbogbo tí ó dára ni yóò wà níbẹ̀
ÌFẸ́
LOVE
Orílèdè náà ní lò Àbò púpọ̀
Àbò
Security
Ọdẹ tí yóò pa ẹkùn, kò múra dáadáa ní o
ỌDẸ
HUNTER
Ilé-iṣẹ́ nla kan tun ti bẹrẹ iṣẹ ni ìlú Ọ̀tà
Ọ̀tà
A town in Ogun State, Nigeria
Ìlú Adà dára fún ọmọlúwàbí láti gbé
ADÀ
A TOWN IN OSUN STATE, NIGERIA
Mo fẹ́ sáré de Abẹ́ igi láti lọ ta ayò
AYÒ
GAME
Bá mi mu ìtẹ̀ wá nínú ilé
Ìtẹ́
Mat
òkò àjẹ́ ò ní bà ẹ́ tìẹ ni yíò ba àjẹ́
Òkò
stone🪨
Àwọn Ràrá wa sí orí ìtàgé fún eré àdídùn
Ràrá
Dwarf
igi Ọ̀mọ̀ wúlò púpọ̀ fún lílò
Ọ̀mọ̀
Tree of the banyan family
Mo nílò orógùn mẹta kún méje tí a rà ni ijẹta
ORÓGÙN
TURNING STICK, TURNER