sentence
stringlengths
14
109
root
stringlengths
2
6
root_meaning
stringlengths
3
64
Bí ògiri Adio kò bá lanu, aláàmù Olusegun kò lè wọ ibẹ
ALÁÀMÙ
LIZARD
Ire ni ojú owó n rí
Ire
Goodness
Agbe sise kò yẹ ọmọlúwàbí rárá
AGBE
BEGGING
Fi ÒRÍ pa ara rẹ kí ó má dàn-án
ÒRÍ
Shea Butter
Mo rán ọmọ ní Obì àti orógbó
Obì
Colanut
ọkọ́ jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú irinṣẹ́ àgbẹ̀
Ọkọ́
Hoe
Ìjì tí ó jà ní alẹ́ àná ni agbára púpọ̀
ÌJÌ
STORM
Igi Osè kì í pẹ́ gbabode
OSÈ
A TYPE OF TREE
Adesoji kò mọ iye owó tí ó kó pamọ́ mọ́
IYE
NUMBER
Àwọn olórin fi ijo sí, nígbà tí àwon oníbàtá dá wọn lára mi
Bàtá
a type Drumbeat
Rí dájú pé o fọ ẹsẹ̀ kí o to wọlé
Ẹsẹ̀
leg
Ọwọ́ Bukola ni orógùn yìí tí kán sí méjì
ORÓGÙN
TURNING STICK, TURNER
Opamade nífẹ̀ẹ́ sí ilà kẹ́kẹ́ ju àbàjà lọ
KẸ́KẸ́
A PECULIAR FACIAL MARK
Kabiyesi náà fí olá jiyọ̀ láàfin
Ọlá
wealth
Gbogbo nkan há gágá fún Adé bíi ọjọ mẹta sẹyìn
Gágá
Tightly
Yorùbá ní ìṣẹ́ kìí déédé ṣẹ bí o bá nídìí
Ìṣẹ́
poverty
Ọ̀mọ tí wọ́n lò lára ilé náà kòtó
Ọ̀mọ
A builder of wall
Ọbẹ̀ ẹyìn dun jẹ iyán
Ẹyìn
palm tree fruit
Mọ fe ra agbọ̀n ní ọjà ní ọlà
Agbọ̀n
Basket
Ilà àbàjà ni won nkọ ni ilu Òwu
Ilà
triber mark
Ogun kò dà bí iyán àti ẹ̀kọ́
OGUN
WAR
àpò ògùn apa Ẹ̀fọn dára láti máa fi sùn
Ẹ̀FỌN
MOSQUITO
Máa ṣọ́ra láti bá Àbẹ̀ọ́ rìn nítorí ìwà
ASA
TALKATIVE
Kẹkẹ tí ba gbogbo igba oko Solape jẹ́
KẸKẸ
A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
Ago mélòó ni ìdíje náà yóò bẹ̀rẹ̀
AGO
CLOCK
Ẹ bá mi rántí mú Awò mi bọ̀ nínú yàrá
AWÒ
SPECTACLE
Fi Abó bu omi wá
Abọ́
plate
Ajá tí yóò sọnù kòní gbọ́ fèrè ọlọ́dẹ
Ajá
Dog
Ìtẹ́ Ọ̀kẹ́rẹ́ náà járọ̀ nígbà tó jábọ́
Járọ̀
To break a fall
Ìyá mi nílò Àyè tí ó gbòòrò fún ọjà wọn
ÀYÈ
SPACE
Ìwó tí o ni ilẹkùn ti o ni kọ́kọ́rọ́ ni wọ́n ki oríkì àwọn ọmọ ìpínlẹ̀ naa
Ìwó
A town in osun state
Mo lọ sí ọjà ni àná
Àná
yesterday
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ta ẹyẹ ní ỌFÀ
Ọfà
catapult
Mo fẹ́ lọ sí ilé ìtọ̀ láti to
Ìtọ̀
Urine
Ẹkún ìyàwó jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú àṣà yorúbá
Ẹkún
Cry
Ọrẹ títa nínú oṣù lamulana dára púpọ̀
ỌRẸ
ALMS
Abẹ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni ìlú ìbàdàn wà
Ìlú
Village
Kunle àti Ṣọla jọ kanko asọ àrán lo s'ode
Àrán
cloth
Ọ̀rẹ́ mi àtàtà ni Kolawole àti Taofiki
Ọ̀RẸ́
FRIEND
Ẹyin akẹ́kọ̀ọ́ mi, ẹ rí dájú pé ẹ ka àwọn ewì yín dáadáa, Ẹ̀RÁN ni ó jẹ fún yín ooo
Ẹ̀rán
Something not to forget
Inú kò gbọ́dọ̀ bí Baba aláwò, kí ó fi ajá bọ ifá
IFÁ
god of divination
Ẹ̀KỌ̀ ẹlẹ́kọ̀ ni ẹ̀gbà ẹlẹ́gbà
Ẹ̀KỌ̀
Abandoned
Ọmọ ìlú Ọ̀la ni alaga tuntun ni ìjọba ìbílẹ̀ rẹ
Ọ̀LÀ
a town in Osun State
Ilá pele ti Ṣọla ko ni aburo baba re fi dá mọ̀
Ilà
triber mark
Ẹ̀yà ni o ma ń fi ìran kan yàtọ̀ sí òmíràn
Ẹ̀YÀ
Tribe
Ayò ọlọpọlọ gbáà ni ayò ọlọ́pọ́n
AYÒ
GAME
À-kúkú-bí, ó sàn jù kí ènìyàn bí ọ̀dẹ̀ ọmọ lọ
Ọ̀DẸ̀
IMBECILE
idanilẹkọ yóò wáyé lọla nipa aràn
Aràn
worm
Àwọn ọmọ ile-iwe náà bu ọ̀wọ̀ fún akẹgbẹ won to se dáadáa nínú ìdíji oníléjilé
Ọ̀wọ̀
honour
ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn odẹ ló sun rárà ní bi igbeyawo
Rárà
A type of song/elegy
Àwọn ìkókó yìí kò mọ ọtun yàtọ̀ sí òsì rárá
ÌKÓKÓ
BABY
Igun ilé ni a kò àdá wa sí
IGUN
CORNER
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fi orin dà wa lára yá
Orin
music
Òkú tí o kú ni a sin sí itẹ́
Itẹ́
Burial ground
Ba mi já orín bọ̀ wá ní oko
Orín
chewing stick
Ogún ti àwọn òbí Tade fi sílẹ̀ fún un titó lo aye
OGÚN
INHERITANCE
Ẹ̀yin wo lẹ n pariwo níbè yẹn
Ẹ̀yin
Those
Iṣẹ igbà hìhun ni Ishọ̀la yan láàyò
Igbà
rope use to climb palm tree
Ọ̀lẹ ni Àlàmú kòlè kọ igba ebè l'oko
Ọ̀le
Lazy
okó ẹṣin yìí gùn ju àwọn èyí tí ó wà nínú ọgbà lọ
Okó
penis
Ẹ̀ya ti o wà ní ara rẹ̀ kọ jà ohun ti a lè fẹ nu sọ
Ẹ̀ya
Tears
Kòsí ohun ti gaga ọwọ̀ kan le se
Gaga
A piece
Ọ̀kan lára àwọn ìdí náà buru gán
Idì
Eagle
Igi ìgbá yìí so ní ọdún yìí púpọ̀
Ìgbá
locus
Ọmọ tí ó jí gègé mi nìyí
STEAL
Kì bá dára kí o sá fún àwọn ọdaju ènìyàn yẹn
RUN AWAY
Ǹjẹ́ kìí se aago mẹ́ta ni ẹ padà fi ìpàdé sí
AGO
CLOCK
Akin lo járọ́ ti Ṣọla pa fún wa
Járọ́
To expose a lie
Ohun tí Adé se fún àbúrò rẹ̀ burú gan
Ohun
Thing
Gbiyanju kí o lọ sí ilé ìwòsan fún iwò ojú
Iwò
spectacle
iná jó ilé náà
Iná
Fire
Oyebisi fẹ́ dé ọ̀dọ̀ àyò rẹ̀ lókè odò
ÀYÒ
FAVORITE
kí olùwà fi ìtọ́ ràn wá lọ́wọ́
Ìtọ́
Guide
Bàbá ran ọmọ ní ike ní ọjà
Ike
plastic
Iná ko jẹ ki awọn adiẹ náà gbádùn
Iná
Lice
Òdo ni Àlàmú gba nínú idanwo to ṣe
Òdo
Zero
ọ̀fà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí o gbajúgbajà ní ìpínlẹ̀ kúárà
ọ̀fà
city in kwara state
Ojo rọ̀ ni ọsẹ to kọjá
Ọsẹ
Week
Adura Bukọ́la gbà nígbà tí wọn fi ire rẹ le lọwọ
Ire
Goodness
Mo nífẹ̀ẹ́ láti ra Àgò mìíràn fún àwọn adìẹ mi
ÀGÒ
THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN
ỌSÀN tí o wà ní Orí igi náà ti pọ́n
Ọsàn
Orange
Adukẹ́ gún iyán nínú odó
Odó
Mortal
Kí ojú máa ríbi gbogbo ara lò gun rẹ̀
Ara
Body
ìwọ àti èkejì rẹ ẹ Pin ọsán yìí Àbò
Àbò
Half
Èmi ati ìyàwó fẹ́ lọ sí bi ayẹyẹ ní ọ̀la
Ọ̀la
tomorrow
Ẹ̀re akọni ọdẹ náà wà ní ẹnu ìloro ìlú wọn
Ère
Statue
Mo dá arábìnrin náà ni oko owò
Owò
business
Eku ilé kò ṣe gba ojú bọ̀rọ̀ fún
EKU
RAT
Ike yìí mọ rẹwà púpọ̀
Ike
plastic
Mo ṣe àkíyèsí wípé àwọn Àlàmú ma ń ní ìwà púpọ̀
ÀLÀMÚ
A MALE NAME
Nínú ìjànbá ọkọ̀ to waye gaga irun ori ẹnìkan kò jona
Gaga
A piece
Dókítà òyìnbó tí gbà á ní ìmọ̀ràn pé kí ó wá gba abẹ́rẹ́ titanọọsi sí ojú egbò rẹ̀ láti dènà aburú ọjọ́ iwájú
EGBÒ
WOUND
Ẹ bá mi pé ìyá ìkókó pé mo fẹ́ rí i
ÌKÓKÓ
BABY
Ọgbọ̀n náírà ni mo ra ọsàn ẹyọ̀kan l'ọja
Ọgbọ̀n
Thirty
ọbẹ̀ ọ́yọ́ máa dùn jẹ́ ẹ̀bà tútù
Ọ́YỌ́
VEGETABLE
Ṣọla ati awọn akẹgbẹ tó jọ kò ọ̀wọ́ rin, nígbà tí wọn jáde ile-iwe
Ọ̀wọ́
Group/ Collectively
Ìsàlẹ̀ ọrọ̀ a máa ní ẹ̀gbín ní ọ̀pọ̀ ìgbà
ỌRỌ̀
WEALTH
kínni ìdí tí Akin se n sá lọ?
Ìdí
Reason
Iṣẹ ọsẹ ni ìyá àgbà n ṣe
Ọsẹ
Soap
Fáṣítì ìjọba àpapọ̀ ti Ilé-Ifè dára púpọ̀
IFẸ̀
A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA