sentence
stringlengths 14
109
| root
stringlengths 2
6
| root_meaning
stringlengths 3
64
⌀ |
|---|---|---|
Ówo tí ó sọ mí ní igi imú ni kò jẹ́ kí n mi dáadáa
|
ÓWO
|
BOIL
|
Abọ́ ayọ́ ni ọmọ náà fi n jẹun
|
Ayọ́
|
Aluminum
|
Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù ní mo já orín náà
|
Orín
|
chewing stick
|
kí ni wọn mú oyún wúndíá se ní òkò
|
Òkò
|
A town in Oyo state
|
Orogún ìyá Kọ́lá lo ràn-án lọ́wọ́
|
OROGÚN
|
RIVAL
|
Ere ṣíṣá ni iṣẹ́ ẹṣin
|
ẸSIN
|
HORSE
|
Wọ́n dá arákùnrin náà dúró sílé ìwòsàn ní torí ẹ̀ya ara rẹ̀
|
Ẹ̀ya
|
Tears
|
Ìdí tí Gboyega ko se wa sí ibi isẹ ko ye mi
|
Ìdí
|
Reason
|
Ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN ni ko jòkó sí
|
Ọ̀tún
|
right
|
Eku àgó mẹ́ta ni a bá nínú omi inú ada
|
ÀGÓ
|
A TYPE OF RAT
|
Obì inú kókó náà so púpọ̀
|
Obì
|
Colanut
|
Ọwọ́ ọmọ náà yá níbi ọ̀wẹ búbù
|
Ọ̀wẹ
|
MORSEL
|
Ọ̀TÙN jẹ ara olú ìlú ìpínlẹ̀ èkìtì
|
Ọ̀TÙN
|
A city in Ekiti
|
Ọ̀kan lára erè ìdárayá ni bọọlu gbigba wà
|
Eré
|
Play/Drama
|
Ọkan lára àwọn akọni ní lẹ̀ yoruba ni Ajagúnlá tí o tẹ ìlú ìlá do
|
Ìlá
|
a town in Osun state
|
Èṣù ni Ogbẹni Akintọla yìí o, òun ni ó dá áwọ̀ sílẹ̀ láàárín Ọlá àti Ìbùkún
|
ÈṢÙ
|
DEVIL
|
okó ní ọmọkùnrin ń fi se ọkọ obìnrin
|
Okó
|
penis
|
Mo fẹràn ìlù púpọ̀ níbi àríyá
|
Ìlù
|
drum
|
Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí mo fẹràn jùlọ
|
Ẹ̀kọ
|
Local food derived from maize
|
OLORÌ ọba ìlú mi rẹ̀wá púpọ̀
|
OLORÌ
|
QUEEN
|
Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá
|
KẸKẸ
|
A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH
|
Ìlú Ọ̀rẹ̀ ni ìyàwó mi bímọ sí
|
Ọ̀RẸ̀
|
A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA
|
Ìgbà ko tọ́ lọ bi orere
|
Ìgbà
|
Time
|
Gbogbo àwọn ọdẹ abúlé wa ti gbára dì láti kojú ìkokò ọdaju náà
|
ÌKOKÒ
|
HYENA
|
Mo bẹ̀rù ọmọ náà púpọ̀, nítorí pé asa ni
|
ASA
|
TALKATIVE
|
Agbè yìí ti lu nìdí
|
AGBÈ
|
BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER
|
Ajá jẹ gbogbo egun náà tán
|
Egun
|
Bone
|
ọkùnrin tó sun rárà fún ọkùnrin ẹgbẹ rẹ̀
|
Rárà
|
A type of song/elegy
|
Àwọn àgbà ló lè yanjú ọ̀rọ̀ yìí
|
ÀGBÀ
|
ELDERLY PERSON
|
Irọ́ ni Bola n pa fún àwọn òbí rẹ̀, ṣugbọn àbúrò rẹ̀ lo járọ́ rẹ̀
|
Járọ́
|
To expose a lie
|
Pí Padé ni ilẹkun ilé iṣẹ́ wà di bí a ṣe ń sọ̀rọ̀ yii
|
PADÉ
|
TO SHUT, TO CLOSE UP
|
Ó ti rẹ ẹyẹ agbe yìí débi wípé kò lè fò dáadáa mọ́
|
AGBE
|
A TYPE OF BIRD
|
Iya àgbà ran Fọlákẹ́ ni Erèé l'ọja
|
Erèé
|
Beans(coupea)
|
Baba gbìyànjú láti ré ègún kúrò lórí àwọn ọmọ
|
Ègún
|
Spell, curse
|
Olóyè jagun gbìyànjú láti dáàbò bo ìlú rẹ
|
Jagun
|
A military title
|
Ẹranko kò ní ohun méjì tí o fi ń se agbára kọjá ìwo
|
Ìwo
|
Animal horn
|
Ókéré gbádùn ẹyìn jíjẹ
|
Ẹyìn
|
palm tree fruit
|
Ọ̀ọni fi ìrù rẹ na ẹkùn ní ojú
|
Ìrù
|
tail
|
Tí ẹ kò bá sà àwọn isẹpẹ igi náà dáadáa, ebè kíkọ náà kò ní yá
|
SÀ
|
PICK
|
Ní aláìsí ìṣẹ̀lẹ̀, kì í sí ìtàn
|
ÌTÀN
|
STORY
|
Ẹ̀re agbabọ́ọ̀lù náà wà ní pápá ẹgbẹ agbabọ́ọ̀lù rẹ̀
|
Ère
|
Statue
|
Owò tí ènìyàn ba mọ ni kí ó tẹra mọ́
|
Owò
|
business
|
Ọmọ náà ní ẹ̀jẹ̀ púpọ̀ lára
|
Ẹ̀jẹ̀
|
Blood
|
Ọjọ́ tí ẹ bá lọ sí oko, ẹ dákun ẹ bá mi gé okùn agba bọ̀
|
AGBA
|
A TYPE OF ROPE FOUND IN FOREST
|
ìyá ran ọmọ ní Abó ni oja
|
Abọ́
|
plate
|
Ọ̀wẹ tí ẹnu rẹ bá gbà ní kí ó máa bù
|
Ọ̀wẹ
|
MORSEL
|
Ẹ sáré bá Ìyá Ìtùnú mú ife kan wá
|
IFE
|
CUP
|
Lọ sun ilẹ̀ tí mo gbé sí èyìnkùlé
|
Sun
|
To burn
|
Ọmọ ìlú Òró ni ìyàwó mi
|
ÒRÓ
|
A CITY IN KWARA STATE, NIGERIA
|
Egbò náà tí di ọyún sí inú gan-an ni o
|
ỌYÚN
|
TUMOR
|
Àwọn amọ̀kòkò pọ̀ ni abúlé wa
|
ÌKÒKÒ
|
CLAY RESERVOIR
|
Inú igbó ní wón sin òkú ẹni ti o bá ní iké sí
|
Iké
|
hunchback
|
Mo bẹ̀rù awọn ọmọ bẹrẹ púpọ̀
|
BẸRẸ
|
AN AREA IN IBADAN, OYO STATE
|
Àwọn Agbè-fún-ọba rí pé àwọn doọ̀là àwọn ọmọ ìlú lọ́wọ́ àwọn ọdanran ni ÀYÈ
|
ÀYÈ
|
ALIVE
|
Ọjà ni Ade ti bá ọrẹ rẹ atijọ pade
|
Ọjà
|
market
|
Mo ti fi ìgbà kan jẹ ejò ỌKÁ rí
|
ỌKÁ
|
COBRA
|
Àwọn olórin fẹràn Abo púpọ̀
|
Abo
|
Female
|
Ilé-Ifè ni ìran Yorùbá ti sẹ̀ wá
|
IFẸ̀
|
A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA
|
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní kó Ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ síáyẹ́nsì
|
Ẹ̀KỌ́
|
Knowledge
|
Bàbá naa jẹ́jẹ̀ pe awon kòní na ọmọ náà
|
Jẹ́jẹ̀
|
To make a vow
|
Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi
|
KẸ́KẸ́
|
A PECULIAR FACIAL MARK
|
Àgbẹ̀ náà fí inú oko rẹ kí àwọn irú náà le dínkù
|
Irù
|
tsetse fly
|
Olóńgbò tó jẹ́ ẹja mi lo jẹ́ kí n jẹ Àmàlà mi ni àsán
|
ÀSÁN
|
EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT
|
Ìgbà tí Bola jẹun tan ni o sun
|
Ìgbà
|
Time
|
mo nífẹ̀ẹ́ sì ẹran ògúnfe ni jíjẹ
|
Ẹran
|
Meat
|
ÀPÀ ọmọ kìí ni dúkìá tó ní láárí kan pàtó
|
Apà
|
Spoiler
|
Mo nífẹ̀ẹ́ sí kíkọ́ èdè Ẹ̀GBÁ
|
Ẹ̀GBÁ
|
NAME OF A TRIBE IN YORÙBÁ KINGDOM
|
Njẹ o ma wá sí ilé ikẹkọ ní ọ̀la
|
Ọ̀la
|
tomorrow
|
Gágá ni ọnà há ni ẹnu ọnà abawole sile igbagbo náà
|
Gágá
|
Tightly
|
Ẹ jẹ́ kí a bọ̀wọ̀ fún Ọ̀gá wa dáadáa
|
Ọ̀GÁ
|
MASTER
|
Ẹní àrá bá pa kìí sun silẹ
|
Àrá
|
thunder
|
Diẹ loku ki ọmọ jabọ́ lẹyìn ìyá ìkókó nígbà tí ọ̀já rẹ tu lojiji
|
Ọ̀já
|
Rapper to mount baby
|
Ẹyẹ agbe mẹ́ta ni mo ṣe alabapade lọ́nà oko
|
AGBE
|
A TYPE OF BIRD
|
Èdè ni o ma ń sọ ìran tí ènìyàn ti wá
|
Èdè
|
Language
|
Wọn pe ẹranko tó ní ìwo ìgbín yọjú
|
Ìwo
|
Animal horn
|
Àwọn Agbè-fún-ọba ní láti pàdé ni ìlú Ìbàdàn
|
PÀDÉ
|
TO COME TOGETHER
|
Rí dájú pé o pe ògèdè sí oúnjẹ kí o jẹ́
|
Ògèdè
|
incantation
|
Àṣà radarada gbáà ni kí ènìyàn máa rin ní ìhòòhò
|
ÀṢÀ
|
CULTURE
|
òkúta tí ọmọ náà jù ORÍ ni o ti bá ewúrẹ́
|
ORÍ
| null |
Gbé ìkòkò náà bá mi ní ọ̀dẹ̀
|
Ọ̀DẸ̀
|
PASSAGE
|
Àgbò tí ìwo rè bá sẹ́ kò se pa iléyá
|
Ìwo
|
Animal horn
|
Ọdẹ pa ikún jẹ ní oko
|
Ikún
|
A kind of Squirrel
|
Owó ní àkàndùn ti mu ọmọ náà
|
Ọwọ́
|
Hand
|
Ẹṣin ọba ìlú ìgbẹ́kẹ̀lé kú ní àná
|
ẸSIN
|
HORSE
|
Ẹyin meji ni Ade fi sori ounjẹ rẹ̀
|
Ẹyin
|
Egg
|
ỌSÁN ìlù náà já nígbà tí akọrin lòó
|
Ọsán
|
One of the rope used to tie talking drum
|
Akinola n sáré gẹ́gẹ́ bíi ẹ́gbọ́n rè
|
Gẹ́gẹ́
|
Exactly
|
Ẹ̀tù, ọta ati ààyá ni o wà nínú ìbọn ọdẹ náà
|
Ààyá
| null |
Ọ̀rọ̀ ẹnu Alarape kò dára tó
|
Ọ̀RỌ̀
|
WORDS
|
Bàbá mi lo kọmi bí a ṣe ń ṣe Ẹ̀TÙ
|
Ẹ̀TÙ
|
GUN POWDER
|
won ti gbe igbá ọsẹ le ọmọ náà lórí ki àṣírí to tu
|
Igbá
|
Calabash
|
Ọbẹ̀ ilá dara fún Ọkùnrin tí àtọ̀ rẹ sàn
|
Ilá
|
Okro
|
Àdá ni ó fi pa ẹranko ẹhànnà náà
|
ÀDÁ
|
CUTLASS
|
Ọjọ́ tí mo bá tún rí ọ pé o ṣe agbe, mo máa nà ọ́
|
AGBE
|
BEGGING
|
Àlàmú ni oríkì tí ìyà àgbà fún un mi
|
ÀLÀMÚ
|
A MALE NAME
|
Gba ìparí yìí kí o máa fi ra Ekundayọ lórí
|
ÀWÙJẸ̀
|
SOFT SPOT
|
Kòsí ààyá kankan nínú ìbọn bàbá ọdẹ náà mọ́
|
Ààyá
| null |
Rí dájú pé o lọ sí ilé ìtọ̀ kí o tó sùn
|
Ìtọ̀
|
Urine
|
Gbogbo Igbìyànjú Awẹle láti di aya ni ọ̀dẹ̀ Àyànwande lo jásí asán
|
ASÁN
|
VAIN
|
Ile ẹ̀kọ́ gbogbo nise ti ìlú ìré ni Ariyọ̀ ti kàwé
|
Ìré
|
A town in Osun State, Nigeria
|
Are LLMs Good Text Diacritizers? An Arabic and Yorùbá Case Study
We investigate the effectiveness of large language models (LLMs) for text diacritization in two typologically distinct languages: Arabic and Yoruba. To enable a rigorous evaluation, we introduce a novel multilingual dataset MultiDiac , with diverse samples that capture a range of diacritic ambiguities. We evaluate 14 LLMs varying in size, accessibility, and language coverage, and benchmarked them against 6 specialized diacritization models. Additionally, we fine-tune four small open-source models using LoRA for Yoruba. Our results show that many off-the-shelf LLMs outperform specialized diacritiztion models for both Arabic and Yoruba, but smaller models suffer from hallucinations. Fine-tuning on a small dataset can help improve diacritization performance and reduce hallucination rates.
Cite this work:
@misc{toyin2025llmsgoodtextdiacritizers,
title={Are LLMs Good Text Diacritizers? An Arabic and Yor\`ub\'a Case Study},
author={Hawau Olamide Toyin and Samar M. Magdy and Hanan Aldarmaki},
year={2025},
eprint={2506.11602},
archivePrefix={arXiv},
primaryClass={cs.CL},
url={https://arxiv.org/abs/2506.11602},
}
- Downloads last month
- 15