MultiDiac / yor_dev.csv
herwoww's picture
Upload folder using huggingface_hub
893cf10 verified
sentence,root,root_meaning
Mo fẹ́ràn iwò ojú rẹ púpọ̀,Iwò,spectacle
Owe Yoruba wipe àrò méta kìí d'ọbẹ̀ nù,Àrò,stone meant for cooking
Ogunleye pá ẹran igbẹ mẹ́ta lóru òní mọ́júmọ́,Ẹran,Meat
Ao bẹ ẹ̀sẹ̀ òbí lára ọmọ,Ẹ̀sẹ̀,SIN
Bàbá ṣe Ìrìnàjò lọ sí ibi tí Ará àwọn mọlẹbi wà,Ará,related people
Àgbọn tí ó wà ní orí igi náà kéré púpọ̀,Àgbọn,coconut
"Bí ọmọdé bá dá ẹ̀jẹ́,ọjọ́ náà ni mọ̀",Ẹ̀jẹ́,convenant
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ irú ní jíjẹ má ń fọ ìdọ̀tí ojú,Irú,locust beans
Ajá tóyó kìí bá àìyó seré,Ajá,Dog
Ọmọ náà yọ ikun ní imú,Ikun,Mucus
Ifá kìí rí gbogbo nǹkan tán,IFÁ,god of divination
Afárá tí àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ ń gbà de ilé ẹ̀kọ́ wọn tí já,AFÁRÁ,BRIDGE
Ẹja ti ìwọ̀ mi gbe lo tóbi jù,Ìwọ̀,Hook
Ọbẹ̀ yìí tí ni ata jù,ỌBẸ̀,SOUP
Àrá san nígbà tí àwon akẹ́kọ̀ọ́ fi ọwọ́ gbe òjò,Àrá,thunder
Ife kan ni odiwon àgbo tí bàbá ṣe fún Dúpẹ́,IFE,CUP
Bàbá mi kò fi ọwọ́ sí kí n fẹ́ ẹ̀yà míràn ni ìyàwó,Ẹ̀YÀ,Tribe
Akintunde fi ìwọ̀ pa òjìjí méjì ni àn,ÒJÌJÍ,A LOCAL NAME OF A FISH
Olú ni ilé-ẹ̀kọ́ mi nínú gbogbo àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀,OLÚ,SUPERIOR
Apá kejì fíìmù náà ni ìtàn náà parí sí,Apá,Hand
Ìwọ ati Adé ni yóò lọ fún ìdíje òlím,Ìwọ,You:
A le t'ori kí itọ́ tán lẹ́nu kí òrò tán,Itọ́,Saliva
Awọn olowo lo n ra aṣọ àrán nígbà tí o ṣẹṣẹ jade,Àrán,cloth
gbogbo igi oro ti ó wà ní àyíká yìí ti gbabode,ORO,A TYPE OF TREE
Ta ìrẹsì Ẹ̀kún rọ́bà fún ìyàwó mi,Ẹ̀kún,Fullness
Ẹ̀yìn ni Sọla joko sí,Ẹ̀yìn,Back
Egun hiha ni àwọn obìnrin jẹ fún àwọn ọkọ wọn,Egun,Bone
Àwọn àgbàlagbà ilé tí dá sí ọ̀rọ̀ náà,Ọ̀RỌ̀,WORDS
Opamade nífẹ̀ẹ́ sí ilà kẹ́kẹ́ ju àbàjà lọ,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK
Òógùn tí ó ń bọ̀ lára ẹ̀gbọ́n Olasode kò mọ ni kékeré,ÒÓGÙN,SWEAT
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ se ìrìn-àjò lọ sí ibití àwọn ẹ̀yà ègùn wà,Ègùn,A tribe in Lagos
Àwọn ará ìlú Òdí yan alága tuntun,Òdí,A town in bayelsa
Agbọ́n ta mí ní oko lànàá,Agbọ́n,wasp
"Adewale ọmọ mi, ó gbọ́dọ̀ mo bí a ṣe ń tọju nkan ìní rẹ dáadáa, kí ayé má bà pé ọ́ ni ÀPÀ ọmọ",Apà,Spoiler
Oró inú ọmọ ènìyàn ó burú ju ti ejò lọ,ORÓ,"VENON, POISON"
Ìlú ọ̀fà ni mo ti ka ìwé,ọ̀fà,city in kwara state
Múra sí iṣẹ́ ọ̀rẹ́ mí má se ya ọ̀lẹ,Iṣẹ́,work
"Elubọ yìí kò kúnná tó, a ní láti fi ajọ̀ jọ̀ọ́",AJỌ̀,SIEVE
Mo fẹ́ ìtọ́ sí ònà fún ìgbéga,Ìtọ́,Guide
Ìran ti Aduke n wo lo ṣokunfa bi igbá náà se fọ,Igbá,Calabash
Kẹ̀kẹ́ bàbá àgbà kò ní ìjánu mọ́,KẸ̀KẸ́,BICYCLE