sentence,root,root_meaning Ówo tí ó sọ mí ní igi imú ni kò jẹ́ kí n mi dáadáa,ÓWO,BOIL Abọ́ ayọ́ ni ọmọ náà fi n jẹun,Ayọ́,Aluminum Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù ní mo já orín náà,Orín,chewing stick kí ni wọn mú oyún wúndíá se ní òkò,Òkò,A town in Oyo state Orogún ìyá Kọ́lá lo ràn-án lọ́wọ́,OROGÚN,RIVAL Ere ṣíṣá ni iṣẹ́ ẹṣin,ẸSIN,HORSE Wọ́n dá arákùnrin náà dúró sílé ìwòsàn ní torí ẹ̀ya ara rẹ̀,Ẹ̀ya,Tears Ìdí tí Gboyega ko se wa sí ibi isẹ ko ye mi,Ìdí,Reason Ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN ni ko jòkó sí,Ọ̀tún,right Eku àgó mẹ́ta ni a bá nínú omi inú ada,ÀGÓ,A TYPE OF RAT Obì inú kókó náà so púpọ̀,Obì,Colanut Ọwọ́ ọmọ náà yá níbi ọ̀wẹ búbù,Ọ̀wẹ,MORSEL Ọ̀TÙN jẹ ara olú ìlú ìpínlẹ̀ èkìtì,Ọ̀TÙN,A city in Ekiti Ọ̀kan lára erè ìdárayá ni bọọlu gbigba wà,Eré,Play/Drama Ọkan lára àwọn akọni ní lẹ̀ yoruba ni Ajagúnlá tí o tẹ ìlú ìlá do,Ìlá,a town in Osun state "Èṣù ni Ogbẹni Akintọla yìí o, òun ni ó dá áwọ̀ sílẹ̀ láàárín Ọlá àti Ìbùkún",ÈṢÙ,DEVIL okó ní ọmọkùnrin ń fi se ọkọ obìnrin,Okó,penis Mo fẹràn ìlù púpọ̀ níbi àríyá,Ìlù,drum Ẹ̀kọ jẹ́ oúnjẹ tí mo fẹràn jùlọ,Ẹ̀kọ,Local food derived from maize OLORÌ ọba ìlú mi rẹ̀wá púpọ̀,OLORÌ,QUEEN Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH Ìlú Ọ̀rẹ̀ ni ìyàwó mi bímọ sí,Ọ̀RẸ̀,"A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA" Ìgbà ko tọ́ lọ bi orere,Ìgbà,Time Gbogbo àwọn ọdẹ abúlé wa ti gbára dì láti kojú ìkokò ọdaju náà,ÌKOKÒ,HYENA "Mo bẹ̀rù ọmọ náà púpọ̀, nítorí pé asa ni",ASA,TALKATIVE Agbè yìí ti lu nìdí,AGBÈ,"BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER" Ajá jẹ gbogbo egun náà tán,Egun,Bone ọkùnrin tó sun rárà fún ọkùnrin ẹgbẹ rẹ̀,Rárà,A type of song/elegy Àwọn àgbà ló lè yanjú ọ̀rọ̀ yìí,ÀGBÀ,ELDERLY PERSON "Irọ́ ni Bola n pa fún àwọn òbí rẹ̀, ṣugbọn àbúrò rẹ̀ lo járọ́ rẹ̀",Járọ́,To expose a lie Pí Padé ni ilẹkun ilé iṣẹ́ wà di bí a ṣe ń sọ̀rọ̀ yii,PADÉ,"TO SHUT, TO CLOSE UP" Ó ti rẹ ẹyẹ agbe yìí débi wípé kò lè fò dáadáa mọ́,AGBE,A TYPE OF BIRD Iya àgbà ran Fọlákẹ́ ni Erèé l'ọja,Erèé,Beans(coupea) Baba gbìyànjú láti ré ègún kúrò lórí àwọn ọmọ,Ègún,"Spell, curse" Olóyè jagun gbìyànjú láti dáàbò bo ìlú rẹ,Jagun,A military title Ẹranko kò ní ohun méjì tí o fi ń se agbára kọjá ìwo,Ìwo,Animal horn Ókéré gbádùn ẹyìn jíjẹ,Ẹyìn,palm tree fruit Ọ̀ọni fi ìrù rẹ na ẹkùn ní ojú,Ìrù,tail "Tí ẹ kò bá sà àwọn isẹpẹ igi náà dáadáa, ebè kíkọ náà kò ní yá",SÀ,PICK "Ní aláìsí ìṣẹ̀lẹ̀, kì í sí ìtàn",ÌTÀN,STORY Ẹ̀re agbabọ́ọ̀lù náà wà ní pápá ẹgbẹ agbabọ́ọ̀lù rẹ̀,Ère,Statue Owò tí ènìyàn ba mọ ni kí ó tẹra mọ́,Owò,business Ọmọ náà ní ẹ̀jẹ̀ púpọ̀ lára,Ẹ̀jẹ̀,Blood "Ọjọ́ tí ẹ bá lọ sí oko, ẹ dákun ẹ bá mi gé okùn agba bọ̀",AGBA,A TYPE OF ROPE FOUND IN FOREST ìyá ran ọmọ ní Abó ni oja,Abọ́,plate Ọ̀wẹ tí ẹnu rẹ bá gbà ní kí ó máa bù,Ọ̀wẹ,MORSEL Ẹ sáré bá Ìyá Ìtùnú mú ife kan wá,IFE,CUP Lọ sun ilẹ̀ tí mo gbé sí èyìnkùlé,Sun,To burn Ọmọ ìlú Òró ni ìyàwó mi,ÒRÓ,"A CITY IN KWARA STATE, NIGERIA" Egbò náà tí di ọyún sí inú gan-an ni o,ỌYÚN,TUMOR Àwọn amọ̀kòkò pọ̀ ni abúlé wa,ÌKÒKÒ,CLAY RESERVOIR Inú igbó ní wón sin òkú ẹni ti o bá ní iké sí,Iké,hunchback Mo bẹ̀rù awọn ọmọ bẹrẹ púpọ̀,BẸRẸ,"AN AREA IN IBADAN, OYO STATE" Àwọn Agbè-fún-ọba rí pé àwọn doọ̀là àwọn ọmọ ìlú lọ́wọ́ àwọn ọdanran ni ÀYÈ,ÀYÈ,ALIVE Ọjà ni Ade ti bá ọrẹ rẹ atijọ pade,Ọjà,market Mo ti fi ìgbà kan jẹ ejò ỌKÁ rí,ỌKÁ,COBRA Àwọn olórin fẹràn Abo púpọ̀,Abo,Female Ilé-Ifè ni ìran Yorùbá ti sẹ̀ wá,IFẸ̀,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní kó Ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ síáyẹ́nsì,Ẹ̀KỌ́,Knowledge Bàbá naa jẹ́jẹ̀ pe awon kòní na ọmọ náà,Jẹ́jẹ̀,To make a vow Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK Àgbẹ̀ náà fí inú oko rẹ kí àwọn irú náà le dínkù,Irù,tsetse fly Olóńgbò tó jẹ́ ẹja mi lo jẹ́ kí n jẹ Àmàlà mi ni àsán,ÀSÁN,EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT Ìgbà tí Bola jẹun tan ni o sun,Ìgbà,Time mo nífẹ̀ẹ́ sì ẹran ògúnfe ni jíjẹ,Ẹran,Meat ÀPÀ ọmọ kìí ni dúkìá tó ní láárí kan pàtó,Apà,Spoiler Mo nífẹ̀ẹ́ sí kíkọ́ èdè Ẹ̀GBÁ,Ẹ̀GBÁ,NAME OF A TRIBE IN YORÙBÁ KINGDOM Njẹ o ma wá sí ilé ikẹkọ ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow Gágá ni ọnà há ni ẹnu ọnà abawole sile igbagbo náà,Gágá,Tightly Ẹ jẹ́ kí a bọ̀wọ̀ fún Ọ̀gá wa dáadáa,Ọ̀GÁ,MASTER Ẹní àrá bá pa kìí sun silẹ,Àrá,thunder Diẹ loku ki ọmọ jabọ́ lẹyìn ìyá ìkókó nígbà tí ọ̀já rẹ tu lojiji,Ọ̀já,Rapper to mount baby Ẹyẹ agbe mẹ́ta ni mo ṣe alabapade lọ́nà oko,AGBE,A TYPE OF BIRD Èdè ni o ma ń sọ ìran tí ènìyàn ti wá,Èdè,Language Wọn pe ẹranko tó ní ìwo ìgbín yọjú,Ìwo,Animal horn Àwọn Agbè-fún-ọba ní láti pàdé ni ìlú Ìbàdàn,PÀDÉ,TO COME TOGETHER Rí dájú pé o pe ògèdè sí oúnjẹ kí o jẹ́,Ògèdè,incantation Àṣà radarada gbáà ni kí ènìyàn máa rin ní ìhòòhò,ÀṢÀ,CULTURE òkúta tí ọmọ náà jù ORÍ ni o ti bá ewúrẹ́,ORÍ, Gbé ìkòkò náà bá mi ní ọ̀dẹ̀,Ọ̀DẸ̀,PASSAGE Àgbò tí ìwo rè bá sẹ́ kò se pa iléyá,Ìwo,Animal horn Ọdẹ pa ikún jẹ ní oko,Ikún,A kind of Squirrel Owó ní àkàndùn ti mu ọmọ náà,Ọwọ́,Hand Ẹṣin ọba ìlú ìgbẹ́kẹ̀lé kú ní àná,ẸSIN,HORSE Ẹyin meji ni Ade fi sori ounjẹ rẹ̀,Ẹyin,Egg ỌSÁN ìlù náà já nígbà tí akọrin lòó,Ọsán,One of the rope used to tie talking drum Akinola n sáré gẹ́gẹ́ bíi ẹ́gbọ́n rè,Gẹ́gẹ́,Exactly "Ẹ̀tù, ọta ati ààyá ni o wà nínú ìbọn ọdẹ náà",Ààyá, Ọ̀rọ̀ ẹnu Alarape kò dára tó,Ọ̀RỌ̀,WORDS Bàbá mi lo kọmi bí a ṣe ń ṣe Ẹ̀TÙ,Ẹ̀TÙ,GUN POWDER won ti gbe igbá ọsẹ le ọmọ náà lórí ki àṣírí to tu,Igbá,Calabash Ọbẹ̀ ilá dara fún Ọkùnrin tí àtọ̀ rẹ sàn,Ilá,Okro Àdá ni ó fi pa ẹranko ẹhànnà náà,ÀDÁ,CUTLASS "Ọjọ́ tí mo bá tún rí ọ pé o ṣe agbe, mo máa nà ọ́",AGBE,BEGGING Àlàmú ni oríkì tí ìyà àgbà fún un mi,ÀLÀMÚ,A MALE NAME Gba ìparí yìí kí o máa fi ra Ekundayọ lórí,ÀWÙJẸ̀,SOFT SPOT Kòsí ààyá kankan nínú ìbọn bàbá ọdẹ náà mọ́,Ààyá, Rí dájú pé o lọ sí ilé ìtọ̀ kí o tó sùn,Ìtọ̀,Urine Gbogbo Igbìyànjú Awẹle láti di aya ni ọ̀dẹ̀ Àyànwande lo jásí asán,ASÁN,VAIN Ile ẹ̀kọ́ gbogbo nise ti ìlú ìré ni Ariyọ̀ ti kàwé,Ìré,"A town in Osun State, Nigeria" Ègún ìdílé kò ní sẹ lórí gbogbo wa,Ègún,"Spell, curse" Mo fún ọmọ ní igba náírà lá ti fi jẹun,Igba,two hundred "Ẹnití a bá torí tiẹ̀ pa adìẹ, iwe ló máa ń jẹ́",IWE,GIZZARD Àná ni ọjọ́ìbí mi,Àná,yesterday Inú òkùn ni mo bá Sọlápé nigba ti mo dé ilé wọn,Òkùn,Darkness Ọkàn lara ọjà to gbajugbaja ni ọjà Gbági ni ìlú Ìbàdàn jẹ,Ọjà,market Bọọlu náà ti kọjá ìlà ki adari ayo to fan fere,Ìlà,line Ètò ìṣúná fún àwọn odi wà lára ohun tí ìjọba mẹnu bà,Odi,dump Ẹ̀yìn ni olukọ ti na akẹkọ náà,Ẹ̀yìn,Back Ogún àpò ẹ̀wà kò lé tó wa lò níbi ìnáwó òkú ìyá àgbà,OGÚN,TWENTY ìjọba kọ́ ilé ìwé ìgbàlódé sí ìlú Òdí,Òdí,A town in bayelsa "Oṣù tó ń bọ̀, ní ọ̀wẹ̀ yóò kàn mí",Ọ̀wè,A COMPANY SUMMONED TO ASSIST ONE OF THEIR MEMBER IN MANUAL LABOR "Ẹ̀sín tí wèrè yóò ṣe, kìí jẹ́ kí ó kú bọ̀rọ̀",Ẹ̀SÍN,SHAME Pátákó yìí kò sí fún kíkọ ikọkukọ,PÁTÁKÓ,"PLANT, BOARD" "Èṣù má ṣe mí, ọmọ ẹlòmíràn ni kí o ṣe",ÈṢÙ,DEVIL Ẹkùn jẹ́ ọ̀kan lára ẹranko tó rẹ wà,Ẹkùn,Leopard Ẹja nla ni ìwọ̀ ọmọ náà gbé,Ìwọ̀,Hook Akinyemi se ọgbà fún àwọn ẹran rẹ̀,Ọgbà,Garden Ogunleke mú ejò ọkà wá sí inú abúlé ni ÀYÈ,ÀYÈ,ALIVE Ọmọ tí ntà ÒRÍ kiri kọjá ní òwúrọ̀,ÒRÍ,Shea Butter Àwọn agbófinró fi ìpá dára sí ọ̀daràn náà lára,ÌPÁ,KICK Ojú egbò náà nílò ìtọ́jú gidigidi,EGBÒ,WOUND Itan ni Mobolaji fi ṣèse níbi ìjàmbá ọkọ̀,ITAN,THIGH Ìkokò ńlá kan wà ní agbègbè oko wa nígbà kan,ÌKOKÒ,WOLF Ẹṣin Ọba ti fi pátákò rẹ gbá akódà lẹ́nu,PÁTÁKÒ,HOOF "Ìjì kìí jà, kí ó dà omi inú àgbọn nù",ÌJÌ,STORM Olùkọ́ náà fẹ́ràn láti máa mú Egba dání,ẸGBA,CANE A ní láti bẹ̀rẹ̀ díẹ̀ kí a lè rí ọ̀nà náà gbà,BẸ̀RẸ̀,BEND Ara kìí ṣe òkúta ni awọn yorùbá wí,Ara,Body Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mọ odi nítorí Àbò,Àbò,Security "Ọ̀rọ̀ tí a jọ sọ ní àná, ó ti di ọ̀rọ̀ awo o",AWO,SECRET Àgbẹ̀ tí ó lọ sí oko tí kò mú ọkọ́ lọ́wọ́ eyín rẹ̀ ni yíò lò,Ọkọ́,Hoe Adesola sá àsálà fún ẹbọra búburú náà,SÁ,RUN AWAY Àwọn Oladele pa ỌKÁ ńlá kan ní ọ̀sán yii,ỌKÁ,COBRA "Díẹ̀ loku ki n tẹ ejò paramọ́lẹ̀ mọ́lẹ̀, nitori ọgba ni àwọ̀ rẹ̀ ati erupẹ ilẹ̀",Ọgba,Equal Solape gbọ́dọ̀ dé ìlú Ọ̀yun ni kùtùkùtù ọlá,Ọ̀YUN,A TOWN IN KWARA STATE Igi osè pọ̀ nínú oko Baba bàbá mi,OSÈ,A TYPE OF TREE Wo ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN rẹ kí o gbé baagi rẹ,Ọ̀tún,right A ní láti sà àwọn ìdọ̀tí ẹ̀wà náà dáadáa,SÀ,PICK Aràn n yọ ọmọ náà lẹnu,Aràn,worm Ọ̀gá wa ti ń bọ̀ wá sí yàrá ikawe,Ọ̀GÁ,MASTER Àwọn Talabi ni ṣíṣe ni Ìpínlẹ̀ ògùn ni oṣù tó ń bọ̀,ÒGÙN,A STATE IN NIGERIA Ìlú Ọ̀TÙN rẹwà púpọ̀ láti gbé,Ọ̀TÙN,A city in Ekiti "Àrò yẹ nígbà tí Bọ́lá n dáná lọwọ, ọbẹ sì dànù",Àrò,stone meant for cooking Gbogbo àgbọn tí mọ rà ní ọjà lo tí bàjẹ́,Àgbọn,coconut 🥥 Ìlú Ọ̀yun rọrùn láti gbé púpọ̀,Ọ̀YUN,A TOWN IN KWARA STATE Ẹyẹ idì náà gbé ọmọ Adìẹ,Idì,Eagle Àwọn oníṣòwò ìkòkò a máa jèrè púpọ̀ ní ayé àtijọ́,ÌKÒKÒ,LOCAL POT gbogbo igi afàrà inú oko baami tí dawo tán,Afàrà,Shingle wood olùkọ́ àgbà ra ọkọ̀ fún ìyàwó rẹ̀,Ọkọ̀,CAR Gbogbo ilé kí bàbá kú Àbò,Abọ̀,welcome Ejò isán jẹ́ ejò olóró tí ó burú púpọ̀,ISÁN,A TYPE OF SNAKE (WHICH LIKE SLEEPING) "Láti le tesiwaju, a nílò ìfẹ́ aisẹtan láàárín wa",ÌFẸ́,LOVE Àwọn agbábọ́ọ̀lù jẹ́jẹ̀ atilẹyin wọn fún akọ́nimọ̀ọ́gbá tuntun,Jẹ́jẹ̀,To make a vow Ìkokò kì í fi eegun já afira,ÌKOKÒ,WOLF Kúnlé ra asọ fún àwọn Òbí rẹ̀,Òbí,parent òkò tí a sọ mọ ọ̀pẹ ni ọ̀pẹ ṣọ mọ́ ni,Òkò,stone🪨 "Ẹnití ó bá gbé ọkàn lé Ọlọhun, yóò ní ìyè àìnípẹ̀kun",ÌYÈ,LIVE Ó gbọ́dọ̀ ṣe Ẹ̀rán orin náà dáadáa kí ó tó lè dán mọ ọ lẹ́nu,Ẹ̀rán,Something not to forget Bí èniyàn kò bá dé oko bàbá ẹnìkan kò le mọ̀ bí o ti fẹ̀ tó,Oko,farm Gbogbo ìlú lé arákùnrin náà sí ẹ̀yìn ìlú ní torí wípé iké tí o ní,Iké,hunchback Òní ni owo ọ̀yà yín yóò jẹ́ sísan,OWÓ,Ọ̀YÀ Ọmọ kékeré kan bú sí Ẹkún láàrín ojú ọ̀nà,Ẹkún,Cry Adekunle fẹ́ràn kí ó máa jẹun ní orí òró,ÒRÓ,STAND Àwọn ará ìlú feyikọgbon fẹ́ mọ ìdí ọrọ̀ Agbaakin ìlú naa,ỌRỌ̀,WEALTH Ọta tán nínú ìbọn awọn olè náà ni wọn bá fi ẹsẹ fẹ́ ẹ,Ọta,Bullet Ọ̀pọ̀lọpọ̀ eegún ló wà níbi ayẹyẹ ìfinijoyè,Eegún,masqurade igi oro ti wó lulẹ,ORO,A TYPE OF TREE Ìkà ni olópàá to yinbọn mo ọmọ náà,Ìkà,wicked Ipa wo ni ìwọ là kalẹ̀ fún ọjọ́ iwájú àwọn èwe,IPA,PATH ìlù bàtá ni wọn lù ni ọjọ́ìbí mi,Bàtá,a type Drumbeat Ara àwọn ìlú tí o jẹ́ gbaju gbaja ni ìlú ìwó jẹ́,Ìwó,A town in osun state Kò sí bí àna se kéré tó àna ni àna yíò ma jẹ,Àna,inlaw Ìkà ni Kunle ti o lẹ okuta mo ọrẹ rẹ,Ìkà,wicked Eku àgó náà tí lu Pakute,ÀGÓ,A TYPE OF RAT Ìlú Ọ̀yọ́ ni mo gbé dàgbà,Ọ̀YỌ́,A STATE IN NIGERIA Bàbá aláwò sọ fún àwọn adigun jalè náà pé kí wọn lọ wa Osé Sango wá,OSÉ,A TOOL USED BY SANGO WORSHIPPERS Aya mi mọ iyán gún,Aya,Wife Bi ara kò bá rọ OKÙN ara kòlè rọ adiẹ,Okùn,Rope Àwo mẹ́jọ ni ìyá àgbà sọ wípé mo fọ nígbà tí mo wà ní kékeré,ÀWO,PLATE Ìjọba gbọ́dọ̀ maa san owó ọ̀yà àwọn òṣìṣẹ́ ni kété tí oṣù bá ti parí,OWÓ,Ọ̀YÀ Òjò tí ó rọ̀ ni àná tí ṣiṣẹ́ ìyè fún igi náà,ÌYÈ,LIVE Ṣé o lè tẹ́lẹ̀ mi de Ọ̀rẹ̀ ni Ọ̀tunla,Ọ̀RẸ̀,"A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA" ìyàwó tí wọ́n fẹ́ láìpẹ́ yìí ti bí ọmọ,Ọmọ,child Àìsàn ibà ni Ẹ̀fọn máa ń fà lára,Ẹ̀FỌN,MOSQUITO Ẹ gbé ẹrù náà sí Igun ilé ìdáná,IGUN,CORNER "A nílò isan ni ori ọmọdé, kí a lè gba ibẹ fún ní abẹ́rẹ́",ISAN,VEIN Isan méjì ni àwọn dókítà sọ pé ó já ní ọwọ́ ọmọ ganfe naa,ISAN,VEIN Adewolu ni àyò bàbá rẹ̀,ÀYÒ,FAVORITE Ẹfọ̀n kúrò ní ẹran àfi Pakute pa,ẸFỌ̀N,BUFFALO Ọmọ bíbí ilú ìlá ni oga ọlọ́pàá lorile ede Nigeria tẹlẹ rí,Ìlá,a town in Osun state Ilé ọlá dára púpọ̀ láti gbé,Ọlá,wealth Ọwọ́ tẹ awọn olè ti wọn n da ilu Ọ̀tà láàmú,Ọ̀tà,"A town in Ogun State, Nigeria" Ẹni tí ó ni èkù lo ni ọ̀bẹ,ÈKÙ,CUTLASS/KNIFE HANDLE Ọpẹ́ tí ẹ dá yẹn kéré jọjọ,ỌPẸ́,THANKS Ọ̀já kan ṣoṣo tí ìyá Ìbejí rà logo pọn àwọn ọmọ rẹ mẹrẹrin,Ọ̀já,Rapper to mount baby ọdún kẹta nìyí tí mo ti ń lo ajọ̀ mi,AJỌ̀,SIEVE Igbà lo já ti akọ̀pẹ náà se kan,Igbà,rope use to climb palm tree Mo Sùn ní èbá ọ̀nà lànà,Sùn,Sleep Mọ gbàgbé láti ranmi létí ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow "Bí ògiri Adio kò bá lanu, aláàmù Olusegun kò lè wọ ibẹ",ALÁÀMÙ,LIZARD Ire ni ojú owó n rí,Ire,Goodness Agbe sise kò yẹ ọmọlúwàbí rárá,AGBE,BEGGING Fi ÒRÍ pa ara rẹ kí ó má dàn-án,ÒRÍ,Shea Butter Mo rán ọmọ ní Obì àti orógbó,Obì,Colanut ọkọ́ jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú irinṣẹ́ àgbẹ̀,Ọkọ́,Hoe Ìjì tí ó jà ní alẹ́ àná ni agbára púpọ̀,ÌJÌ,STORM Igi Osè kì í pẹ́ gbabode,OSÈ,A TYPE OF TREE Adesoji kò mọ iye owó tí ó kó pamọ́ mọ́,IYE,NUMBER "Àwọn olórin fi ijo sí, nígbà tí àwon oníbàtá dá wọn lára mi",Bàtá,a type Drumbeat Rí dájú pé o fọ ẹsẹ̀ kí o to wọlé,Ẹsẹ̀,leg Ọwọ́ Bukola ni orógùn yìí tí kán sí méjì,ORÓGÙN,"TURNING STICK, TURNER" Opamade nífẹ̀ẹ́ sí ilà kẹ́kẹ́ ju àbàjà lọ,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK Kabiyesi náà fí olá jiyọ̀ láàfin,Ọlá,wealth Gbogbo nkan há gágá fún Adé bíi ọjọ mẹta sẹyìn,Gágá,Tightly Yorùbá ní ìṣẹ́ kìí déédé ṣẹ bí o bá nídìí,Ìṣẹ́,poverty Ọ̀mọ tí wọ́n lò lára ilé náà kòtó,Ọ̀mọ,A builder of wall Ọbẹ̀ ẹyìn dun jẹ iyán,Ẹyìn,palm tree fruit Mọ fe ra agbọ̀n ní ọjà ní ọlà,Agbọ̀n,Basket Ilà àbàjà ni won nkọ ni ilu Òwu,Ilà,triber mark Ogun kò dà bí iyán àti ẹ̀kọ́,OGUN,WAR àpò ògùn apa Ẹ̀fọn dára láti máa fi sùn,Ẹ̀FỌN,MOSQUITO Máa ṣọ́ra láti bá Àbẹ̀ọ́ rìn nítorí ìwà,ASA,TALKATIVE Kẹkẹ tí ba gbogbo igba oko Solape jẹ́,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH Ago mélòó ni ìdíje náà yóò bẹ̀rẹ̀,AGO,CLOCK Ẹ bá mi rántí mú Awò mi bọ̀ nínú yàrá,AWÒ,SPECTACLE Fi Abó bu omi wá,Abọ́,plate Ajá tí yóò sọnù kòní gbọ́ fèrè ọlọ́dẹ,Ajá,Dog Ìtẹ́ Ọ̀kẹ́rẹ́ náà járọ̀ nígbà tó jábọ́,Járọ̀,To break a fall Ìyá mi nílò Àyè tí ó gbòòrò fún ọjà wọn,ÀYÈ,SPACE Ìwó tí o ni ilẹkùn ti o ni kọ́kọ́rọ́ ni wọ́n ki oríkì àwọn ọmọ ìpínlẹ̀ naa,Ìwó,A town in osun state Mo lọ sí ọjà ni àná,Àná,yesterday Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ta ẹyẹ ní ỌFÀ,Ọfà,catapult Mo fẹ́ lọ sí ilé ìtọ̀ láti to,Ìtọ̀,Urine Ẹkún ìyàwó jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú àṣà yorúbá,Ẹkún,Cry Ọrẹ títa nínú oṣù lamulana dára púpọ̀,ỌRẸ,ALMS Abẹ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni ìlú ìbàdàn wà,Ìlú,Village Kunle àti Ṣọla jọ kanko asọ àrán lo s'ode,Àrán,cloth Ọ̀rẹ́ mi àtàtà ni Kolawole àti Taofiki,Ọ̀RẸ́,FRIEND "Ẹyin akẹ́kọ̀ọ́ mi, ẹ rí dájú pé ẹ ka àwọn ewì yín dáadáa, Ẹ̀RÁN ni ó jẹ fún yín ooo",Ẹ̀rán,Something not to forget "Inú kò gbọ́dọ̀ bí Baba aláwò, kí ó fi ajá bọ ifá",IFÁ,god of divination Ẹ̀KỌ̀ ẹlẹ́kọ̀ ni ẹ̀gbà ẹlẹ́gbà,Ẹ̀KỌ̀,Abandoned Ọmọ ìlú Ọ̀la ni alaga tuntun ni ìjọba ìbílẹ̀ rẹ,Ọ̀LÀ,a town in Osun State Ilá pele ti Ṣọla ko ni aburo baba re fi dá mọ̀,Ilà,triber mark Ẹ̀yà ni o ma ń fi ìran kan yàtọ̀ sí òmíràn,Ẹ̀YÀ,Tribe Ayò ọlọpọlọ gbáà ni ayò ọlọ́pọ́n,AYÒ,GAME "À-kúkú-bí, ó sàn jù kí ènìyàn bí ọ̀dẹ̀ ọmọ lọ",Ọ̀DẸ̀,IMBECILE idanilẹkọ yóò wáyé lọla nipa aràn,Aràn,worm Àwọn ọmọ ile-iwe náà bu ọ̀wọ̀ fún akẹgbẹ won to se dáadáa nínú ìdíji oníléjilé,Ọ̀wọ̀,honour ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn odẹ ló sun rárà ní bi igbeyawo,Rárà,A type of song/elegy Àwọn ìkókó yìí kò mọ ọtun yàtọ̀ sí òsì rárá,ÌKÓKÓ,BABY Igun ilé ni a kò àdá wa sí,IGUN,CORNER Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fi orin dà wa lára yá,Orin,music Òkú tí o kú ni a sin sí itẹ́,Itẹ́,Burial ground Ba mi já orín bọ̀ wá ní oko,Orín,chewing stick Ogún ti àwọn òbí Tade fi sílẹ̀ fún un titó lo aye,OGÚN,INHERITANCE Ẹ̀yin wo lẹ n pariwo níbè yẹn,Ẹ̀yin,Those Iṣẹ igbà hìhun ni Ishọ̀la yan láàyò,Igbà,rope use to climb palm tree Ọ̀lẹ ni Àlàmú kòlè kọ igba ebè l'oko,Ọ̀le,Lazy okó ẹṣin yìí gùn ju àwọn èyí tí ó wà nínú ọgbà lọ,Okó,penis Ẹ̀ya ti o wà ní ara rẹ̀ kọ jà ohun ti a lè fẹ nu sọ,Ẹ̀ya,Tears Kòsí ohun ti gaga ọwọ̀ kan le se,Gaga,A piece Ọ̀kan lára àwọn ìdí náà buru gán,Idì,Eagle Igi ìgbá yìí so ní ọdún yìí púpọ̀,Ìgbá,locus Ọmọ tí ó jí gègé mi nìyí,JÍ,STEAL Kì bá dára kí o sá fún àwọn ọdaju ènìyàn yẹn,SÁ,RUN AWAY Ǹjẹ́ kìí se aago mẹ́ta ni ẹ padà fi ìpàdé sí,AGO,CLOCK Akin lo járọ́ ti Ṣọla pa fún wa,Járọ́,To expose a lie Ohun tí Adé se fún àbúrò rẹ̀ burú gan,Ohun,Thing Gbiyanju kí o lọ sí ilé ìwòsan fún iwò ojú,Iwò,spectacle iná jó ilé náà,Iná,Fire Oyebisi fẹ́ dé ọ̀dọ̀ àyò rẹ̀ lókè odò,ÀYÒ,FAVORITE kí olùwà fi ìtọ́ ràn wá lọ́wọ́,Ìtọ́,Guide Bàbá ran ọmọ ní ike ní ọjà,Ike,plastic Iná ko jẹ ki awọn adiẹ náà gbádùn,Iná,Lice Òdo ni Àlàmú gba nínú idanwo to ṣe,Òdo,Zero ọ̀fà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí o gbajúgbajà ní ìpínlẹ̀ kúárà,ọ̀fà,city in kwara state Ojo rọ̀ ni ọsẹ to kọjá,Ọsẹ,Week Adura Bukọ́la gbà nígbà tí wọn fi ire rẹ le lọwọ,Ire,Goodness Mo nífẹ̀ẹ́ láti ra Àgò mìíràn fún àwọn adìẹ mi,ÀGÒ,THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN ỌSÀN tí o wà ní Orí igi náà ti pọ́n,Ọsàn,Orange Adukẹ́ gún iyán nínú odó,Odó,Mortal Kí ojú máa ríbi gbogbo ara lò gun rẹ̀,Ara,Body ìwọ àti èkejì rẹ ẹ Pin ọsán yìí Àbò,Àbò,Half Èmi ati ìyàwó fẹ́ lọ sí bi ayẹyẹ ní ọ̀la,Ọ̀la,tomorrow Ẹ̀re akọni ọdẹ náà wà ní ẹnu ìloro ìlú wọn,Ère,Statue Mo dá arábìnrin náà ni oko owò,Owò,business Eku ilé kò ṣe gba ojú bọ̀rọ̀ fún,EKU,RAT Ike yìí mọ rẹwà púpọ̀,Ike,plastic Mo ṣe àkíyèsí wípé àwọn Àlàmú ma ń ní ìwà púpọ̀,ÀLÀMÚ,A MALE NAME Nínú ìjànbá ọkọ̀ to waye gaga irun ori ẹnìkan kò jona,Gaga,A piece Dókítà òyìnbó tí gbà á ní ìmọ̀ràn pé kí ó wá gba abẹ́rẹ́ titanọọsi sí ojú egbò rẹ̀ láti dènà aburú ọjọ́ iwájú,EGBÒ,WOUND Ẹ bá mi pé ìyá ìkókó pé mo fẹ́ rí i,ÌKÓKÓ,BABY Ọgbọ̀n náírà ni mo ra ọsàn ẹyọ̀kan l'ọja,Ọgbọ̀n,Thirty ọbẹ̀ ọ́yọ́ máa dùn jẹ́ ẹ̀bà tútù,Ọ́YỌ́,VEGETABLE "Ṣọla ati awọn akẹgbẹ tó jọ kò ọ̀wọ́ rin, nígbà tí wọn jáde ile-iwe",Ọ̀wọ́,Group/ Collectively Ìsàlẹ̀ ọrọ̀ a máa ní ẹ̀gbín ní ọ̀pọ̀ ìgbà,ỌRỌ̀,WEALTH kínni ìdí tí Akin se n sá lọ?,Ìdí,Reason Iṣẹ ọsẹ ni ìyá àgbà n ṣe,Ọsẹ,Soap Fáṣítì ìjọba àpapọ̀ ti Ilé-Ifè dára púpọ̀,IFẸ̀,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA Àwọn Olórò kéde pé orò yóò jáde lọla,ORÒ,A god in Yoruba land Ọ̀tunla ni àwọn agbagba ilé yóò pín ogún,OGÚN,INHERITANCE ògèdè jẹ ohun tí a gbọ́dọ̀ se kí a tó wọ ìgbàlẹ̀,Ògèdè,incantation Gbogbo Abo ni wọ́n ti ni ọkọ tán,Abo,Female "Aya ọmọdé ni ìwà àìgbọràn pọ̀ sí, Egba sì ni ó lè le jáde",ẸGBA,CANE Àwọn dókítà tí ṣe iṣẹ́ abẹ láti lè kó ọyún inú apá ọkùnrin náà kúrò,ỌYÚN,TUMOR Àwọn Kẹ́kẹ́ kò jẹ́ kí a gbádùn igbá tí a gbìn rárá,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH Àgò ni yóò dé adìẹ gbẹyin,ÀGÒ,THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN "IRỌ̀ pípa ni gbogbo ìgbà, kì í jẹ́ kí a nìyí",IRỌ́,LIE Mo nílò kí alagbẹdẹ bá mi rọ ẹyá méjì lónìí,ẸYÁ,TEAR Ìyà Àṣàkẹ́ kì í jẹ́ ọbẹ̀ ọ́yọ́ rárá,Ọ́YỌ́,VEGETABLE Bàbá Abiodun abà arẹ̀sà kúndùn Ìfà púpọ̀,ÌFÀ,FREEBIE Èrè ti Ṣọla jẹ lórí ọjà rẹ̀ lo fi ra asọ ọdún,Èrè,Gain/Profit ìwọ ni o se iku pa ọmọ náà,Ìwọ,You: Akin se àbúrò rẹ ni osẹ́,Ọsẹ́,injury Àwọn Obí n ṣeré ní àyíká,Obí,kid/baby Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà bẹ̀rẹ̀ láti kí Ọ̀gá wọn,BẸ̀RẸ̀,BEND Aró dà sí asọ tuntun ti mo ṣẹṣẹ rà,Aró,Dye Ṣọla ati Bode nlọ ọjà lọla,Ọjà,market Ẹsẹ̀ ni ọta ti ba ọdaràn náà,Ọta,Bullet Ìgbá ti mọ ká ní àná ni mo fí ṣe irú to wa nínú ọbẹ̀ yìí,Ìgbá,locus Ọwọ́ ni olukọ ti fún ọmọ náà lẹ́gba,Ọwọ́,Hand Ìyá àgbà so wípé àsán ni a máa jẹ oúnjẹ alẹ́,ÀSÁN,EATING FOOD WITHOUT ADDING FISH/MEAT Ogunleke ń gbìyànjú láti pá àsá abàmì náà,ÀSÁ,EAGLE "ìyàwó burúkú dùn-ún fẹ́, àna burúkú ni o dùn-ún ni",Àna,inlaw Bá mi dá Ẹ̀kọ wá ní búkà,Ẹ̀kọ,Local food derived from maize Ẹ̀kọ̀ ni ọkùnrin kọ Obìnrin nílé ọkọ,Ẹ̀KỌ̀,Abandoned Oyè jagun nílu Feyikogbon da wàhálà silẹ,Jagun,A military title OLÓRÍ ilé àwọn Talabi ti tẹri gba aṣọ,OLÓRÍ,LEADER Ìyá mi àti orogún wọn nífẹ̀ẹ́ ara wọn dọba,OROGÚN,RIVAL Ríru omi ÒKUN bo ọkò ojú omi náà mọlẹ,Òkun,Ocean itẹ́ ni wọ́n sin àwọn òkú ṣí,Itẹ́,Burial ground Yíyọ́ Ẹkùn t'ojo kọ́ o dábírà ni,Ẹkùn,Leopard Bí àgbẹ̀ bá da oko dáadáa yíò rí èrè níbẹ̀,Oko,farm Ẹ̀kún rọ́bà epo ni mo fẹ́,Ẹ̀kún,Fullness ORÍ ni kí ẹ ma bọ kí ẹ fi òrìsà sílẹ̀,ORÍ, Ọ̀tunla ni ọdún Ògún ni ìlú Ondo,ÒGÚN,god OF THUNDER Olóyè Ọ̀yọ́ Aláàfin ni bàbá mi,Ọ̀YỌ́,A STATE IN NIGERIA Ọdẹ fí ỌFÀ pa ọ̀kẹ́rẹ́ ni orí igi,Ọfà,catapult Ọgbọ́n ọlọgbọ́n ni kìí jẹ kí a pè àgbà ní wéré,Ọgbọ́n,Wisdom "Ṣe ọmọ náà wá sí ilé ìwé,rárá kò wá",Rárá,At all àyà Ṣọla já nígbà tí o gburó ìbọn,Àyà,Chest ìlú òkò jẹ́ ọ̀kan lára ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́,Òkò,A town in Oyo state Òkùn kọni kùn ki onínú má monú,Òkùn,Darkness Gẹ̀gẹ̀ ti Aduke ni mú kí o burẹ́wà,Gẹ̀gẹ̀,A protuberance on the neck Àwọn ilé tí o wà ní Àjá ti wọ́n jù,Àjá,A place in Lagos Apá kan ni ọkùnrin náà ni,Apá,Hand Ọjọ́ ìsinmi tó ń bọ̀ ni ìsìn ìkẹyìn nínú oṣù yii,ÌSÌN,WORSHIP Ìpínlẹ̀ Ògùn náà rẹ̀wá ni ìwọ̀nba,ÒGÙN,A STATE IN NIGERIA Àwọn ìjọba tí ṣe àdéhùn láti san owó òógùn ojú àwọn òṣìṣẹ́,ÒÓGÙN,SWEAT "Pakute tí mo dẹ fún ọ̀ọ́fàn, aláàmù ló mú",ALÁÀMÙ,LIZARD "Àjọ àkọ́kọ́ tí mo dá, ní mo fi ra kẹ̀kẹ́",ÀJỌ,CONTRIBUTION Mo fẹ́ kí a yọ sí ọ̀daràn náà ni òjijì,ÒJIJÌ,SUDDENLY Ọ̀wẹ̀ tí mo gbà ní ọdún tí ó kọjá pé mi púpọ̀,Ọ̀wè,A COMPANY SUMMONED TO ASSIST ONE OF THEIR MEMBER IN MANUAL LABOR ikùn aláboyún naa tóbi púpọ̀,Ikùn,Stomach Oṣù tí ó ń bọ̀ ni ìyá Ayinla máa jáde nílé opó,OPÓ,WIDOW/WIDOWER ẹni tí ò ki ni kú ilé ó pà dànù ẹku Abọ̀,Abọ̀,welcome Igi ọ̀pẹ ẹgbẹ̀rún kan ni a gbìn sí orí ilẹ̀ tuntun náà,Ọ̀PẸ,PALM Ẹ̀KỌ́ ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ kọ́ ní ogbà àwọn ẹranko,Ẹ̀KỌ́,Knowledge Ògùn yìí dára fún ojú ṣíṣú,ÒGÙN,MEDICINE Aràrá ni olùkọ́ ède yorùbá,Ràrá,Dwarf Ó yẹ kí gbogbo sa ipá láti dènà aburú ọjọ́ iwájú,IPÁ,ABILITY Òpó náà kò rí Ẹsẹ̀ fi múlẹ̀ dáradára mọ oooo,ÒPÓ,PILLAR "Ọmọ bíbí ìlú ìré ni Akinyemi, ọ̀rẹ́ Taiwo",Ìré,"A town in Osun State, Nigeria" Ẹ gbìyànjú láti fi ilẹkun ilé sí pí padé,PADÉ,"TO SHUT, TO CLOSE UP" Ọsẹ dúdú ni Adé fi n wẹ̀,Ọsẹ,Soap Igi Afàrà dára fún ilé kíkàn,Afàrà,Shingle wood Mo nílò láti kó àwo bí mẹ́ta lọ sí ilé ẹ̀kọ́,ÀWO,PLATE Osé mẹta ni ó wà ní ilẹ̀ fún nílò ní ọdún yii,OSÉ,A TOOL USED BY SANGO WORSHIPPERS Ọmọ náà gbá iná mú,Iná,Fire🔥 Ẹ Funmi ni ìṣù ọkà mẹ́jọ péré,ỌKÀ,YORÙBÁ LOCAL FOOD Bàbá Orisabunmi pa ejò isán ní ńlá kan ní ọ̀sẹ̀ tó kọjá,ISÁN,A TYPE OF SNAKE (WHICH LIKE SLEEPING) "Àáyá gbọ́n, Ògúngbè gbọ́n",Àáyá,species of monkey "Ní òjijì, òkúta ńlá ré lu ọdẹ náà",ÒJIJÌ,SUDDENLY Mo fi agbọ̀n kó irè oko wá lé,Agbọ̀n,Basket "ijọ́ tí ènìyàn bá dá ẹ̀jẹ́ kìí mọ̀, àyàfi tí ìṣòro bade",Ẹ̀jẹ́,convenant "Ajá tí yóò sọnù, kìí gbó ìfé ọdẹ",ÌFÉ,WHISTLING Ẹ rí i dájú pé Irọ̀ ni àwọn ọmọ tí ẹ fẹ́ kó jọ fún ìdíje yìí,IRỌ̀,AGE MATE Itan mi ti ó tóbi ni kò jẹ́ kí n le sáré dáadáa,ITAN,THIGH kò dára kí ọmọdé máa wo òjìji ara rẹ̀,ÒJÌJI,SHADOW Ìlù àti orin jẹ́ ọmọ ìyá kan náà,Ìlù,drum Agbè bàbá Kọ́lá elẹ́mu tí kún fún ẹmu gidi,AGBÈ,"BIG GOURD, NORMALLY USED BY PALM WINE TAPPER" Ẹ kìlọ̀ fún àwọn ọmọ yín kí wọn má fi Ògún búra èké o,ÒGÚN,god OF THUNDER "A n t'ori Àjà jà,Àjà ní ta lọ njà lẹ́kùnlé òhun",Àjà,Roof Ìsín ni Ìwọ̀ mi gbé wa si òkè odò,ÌSÍN,SMALL CATFISH "Kí á má parọ́, Ìfà ni ó kó bá Fioye",ÌFÀ,FREEBIE ỌSÁN tí ó di ìlù náà mu' jẹ́ kí ohùn dún dáadáa,Ọsán,One of the rope used to tie talking drum Àró pa ẹran ìgbẹ́ bọ̀ l'oko,Àró,Name of person Adìẹ ìyá àgbà ti n yé ẹyin,Ẹyin,Egg "Ibi tí Ìfẹ́ bá wà, ohun gbogbo tí ó dára ni yóò wà níbẹ̀",ÌFẸ́,LOVE Orílèdè náà ní lò Àbò púpọ̀,Àbò,Security "Ọdẹ tí yóò pa ẹkùn, kò múra dáadáa ní o",ỌDẸ,HUNTER Ilé-iṣẹ́ nla kan tun ti bẹrẹ iṣẹ ni ìlú Ọ̀tà,Ọ̀tà,"A town in Ogun State, Nigeria" Ìlú Adà dára fún ọmọlúwàbí láti gbé,ADÀ,"A TOWN IN OSUN STATE, NIGERIA" Mo fẹ́ sáré de Abẹ́ igi láti lọ ta ayò,AYÒ,GAME Bá mi mu ìtẹ̀ wá nínú ilé,Ìtẹ́,Mat òkò àjẹ́ ò ní bà ẹ́ tìẹ ni yíò ba àjẹ́,Òkò,stone🪨 Àwọn Ràrá wa sí orí ìtàgé fún eré àdídùn,Ràrá,Dwarf igi Ọ̀mọ̀ wúlò púpọ̀ fún lílò,Ọ̀mọ̀,Tree of the banyan family Mo nílò orógùn mẹta kún méje tí a rà ni ijẹta,ORÓGÙN,"TURNING STICK, TURNER" Ayọ̀ ni orúkọ ọmọ náà,Ayọ̀,Joy Okùn kìí gùn ko ma ní ibi tí o ti wá,Okùn,Rope Ohùn ẹkún ọmọ náà ni mo gbọ́ tí mo fi jáde síta,Ohùn,Sound Ọjọ ayọ̀ ni ọjọ ti mo jade ni ile-iwe gíga,Ayọ̀,Joy Ọmọ náà pọ́n bi ọ̀lẹ̀,Ọ̀lẹ̀,Local food derived from beans(moimoi) "Ìkokò wọlu, èèmò dé, ọ̀rọ̀ di b'òlọ yà fún mi",ÌKOKÒ,HYENA Ogún maàkì ni ẹni kọ̀ọ̀kan yín gbọdọ̀ gbà,OGÚN,TWENTY Igbìyànjú mi láti la ipa rere nínú ayé yìí kò ní já sí asán,IPA,PATH Solape n fi gégé ìyá náà bú u,Gẹ̀gẹ̀,A protuberance on the neck Àwọn esú jà nínú oko ọ̀rẹ́ mi ni ọdún tí ó kọjá,ESÚ,LOCUST Ọmọ náà fi orí jálé agbọ́n,Agbọ́n,wasp Ewé igi náà járọ̀ sára òwú alantakun,Járọ̀,To break a fall Bàbá Folake sọ wípé ègbo ni òun fẹ́ jẹ,ÈGBO,FOOD DERIVED FROM MAIZE "Ẹ̀yin tí ẹ joko sibẹ̀ yẹn, ẹ fura o",Ẹ̀yin,Those Àyà ni bọọlu ti bá agbabọ́ọ̀lù náà,Àyà,Chest Mo fẹràn láti máà ṣọ èdè gẹ̀ẹ́sì,Èdè,Language Ìwé yìí kò rọrùn ni kíkà,ÌWÉ,BOOK Ẹ ní láti ṣètò bí a ó ṣe pàdé lọla,PÀDÉ,TO COME TOGETHER ikún jẹ ọgẹdẹ ikún n rèdí,Ikún,A kind of Squirrel Àwọn òní agbe náà nínú ọrẹ,ỌRẸ,ALMS "Orí igún kò ṣàdédé pá, ó ní ìtàn tó rọ̀ mọ",IGÚN,VULTURE Ìkòkò mẹwa ló fọ níbi ìjàmbá tó ṣẹlẹ̀ lọ́nà irẹsa,ÌKÒKÒ,CLAY RESERVOIR Adùn gé irun rẹ nitori iná orí,Iná,Lice Ọlè wà nínú ọ̀kẹ́rẹ́ ti bàbá ọdẹ pa,Ọlẹ̀,Foetus Wọn fi ọ̀daràn náà ṣe ẹ̀ṣín ni ojúde ọba,Ẹ̀SÍN,SHAME Mo nílò ikàn méjì péré láti fi jẹ isu mi,IKÀN,GARDEN EGG Mo ra asọ ní ojà laisan owó,Owó,money Ọmọ náà sun yàrá ìyá rẹ̀ nigbati o fi ìsáná seré,Sun,To burn Igbá tí mo fí pọn omi já sí odò lànàá,Igbá,fetcher Olúwa bun àwọn ọkọ àti aya ní Obí tuntun,Obí,kid/baby Ìlú Ọ̀lá ko ju mẹ́ẹ̀lì meji lo sí ìlú Ejigbo,Ọ̀LÀ,a town in Osun State Erè wọ́ ewúrẹ́ náà mì,Erè,Snake (python) Òdo ni ọ bẹrẹ nọ́ḿbà ẹ̀rọ aláàgbéká ti Tolu ń lo,Òdo,Zero Kílódé tí ọ̀rọ̀ òdì jáde lẹnu rẹ,Òdì,other side of something inú yàrá mi kò ní àyè tí ó tẹ́mi lọ́rùn rárá,ÀYÈ,SPACE Igbó mímu ti fẹ́ yí ọmọ náà lórí,Igbó,India helm Àwọn ikán tí ba gbogbo igi náà jé,IKÁN,TERMITE Mo fẹràn láti máà jẹ Edé púpọ̀,Edé,Crayfish Ìlú Ọ̀wọ̀ jé òkan lára àwon ìlú to tóbi jùlọ ní ìpínlè Ondó,Ọ̀wọ̀,A town in Ondo State Ọ̀lẹ̀ ati ẹ̀kọ ni Ṣọla jẹ l'ọsan,Ọ̀lẹ̀,Local food derived from beans(moimoi) Okùn agba ni bàbá fi di iṣu náà wálé,AGBA,A TYPE OF ROPE FOUND IN FOREST Dókítà isegun oyinbo ti o da ìwọ́ ọmọ náà mọ iṣẹ dojú àmì,Ìwọ́,Umbilical cord Adewale alapata nílò láti pọ́n ọ̀bẹ rẹ̀ dáadáa,Ọ̀BẸ,KNIFE Ǹjẹ́ ìwọ ti jẹ Awújẹ rí bí?,AWÚJẸ,A TYPE OF PLANT RESEMBLE BEANS "Taye ati Kehinde ko ga ju ara wọn lọ, ọgba láwọn méjèjì",Ọgba,Equal Ṣé o fẹràn bàtà tí bàbá mi rà lànàá,Irú,type Asọ àrán ni Ade wo jáde l'ana,Àrán,cloth Kínní ipá tí ó sà lórí gbogbo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rẹ?,IPÁ,ABILITY Olóyè Àró n jẹ́jọ́ ni ààfin ọba,Àró,Name of person Àwọn ẹyẹ tí fẹ́rẹ̀ jẹ gbogbo ọkà oko baami tán,ỌKÀ,GUINEA CORN Mo ra Edé ní ọjà láti fi se ọbè,Edé,Crayfish Kẹkẹ tí ba gbogbo igba oko Solape jẹ́,KẸKẸ,A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH Ògédé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní afẹ kí ó joko níbi ayẹyẹ yìí,Ògédé,Only Nínú gbogbo ẹ̀yà tí o wà ní orílẹ̀-èdè àgbáyé ẹ̀yà Yorùbá ló dára jù,Ẹ̀YÀ,Tribe Ilẹ̀ ti mọ kọ fún nnkan ọ̀gbìn ní ọdún yìí tó igba,Igba,two hundred Ẹja òjìjí ṣòro láti pa púpọ̀,ÒJÌJÍ,A LOCAL NAME OF A FISH Mo bẹ Elédùmarè kí ó ṣe mí ní olú ni orile-ede mi,OLÚ,SUPERIOR ìgbà àti àkókò kò dúró dé ẹnìkankan,Ìgbà,Time Àgbá òfìfo ni ó má ń pariwo,ÀGBÁ,BARREL ìdí nì olukọ ti na Ade ni ẹgba,Ìdí,Bottom Tẹ́tẹ́ títa tí padà gba aṣọ ni ara Ibikunle,TẸ́TẸ́,GAMBLING Jẹ́jẹ́ lọmọ náà joko ki Ṣọla tó dọ́dọ̀ rẹ̀,Jẹ́jẹ́,Gently Mọ wọ bàtà sí ẹsẹ̀ rẹ kí o tó jáde,Ẹsẹ̀,leg Ẹ sọ́ra níbi fífi ògùn orí fífọ́ wo inú rírun,ÒGÙN,MEDICINE Ǹjẹ́ mo le rí ọbẹ̀ ẹgusi díẹ̀,ỌBẸ̀,SOUP Àdùnní gbin ewebẹ sínú ọgbà,Ọgbà,Garden Ọ̀mọ pọ̀ láàrín ìlú láti lò,Ọ̀mọ,A builder of wall Akitiyan olùkọ́ Adé láti rí pé ó ṣe àṣeyọrí lo padà jásí asán,ASÁN,VAIN Ọmọ olorì àgbà ní ààfin yìí ni Adekola,OLORÌ,QUEEN Gbogbo ìwé bàbá (D O Fagunwa) ni olùkọ́ wa sọ pé kí á rà,ÌWÉ,BOOK Ìsìn àná dùn momi púpọ̀ gan-an,ÌSÌN,WORSHIP Ìjọba fi rọ̀gùnrọ́gún owó sí ilé ìwé àwọn odi,Odi,dump Mo sún fún ọ̀rẹ́ mi nítorí ìwà rẹ̀,Sún,Shift Kò sí ohùn tí ènìyàn kò le fi àrà dá,Àrà,unique (wonder) Ọbẹ̀ ilá ní ìyá àgbà se fún bàbá l'ana,Ilá,Okro "Tí o bá ti jí, dákun gbìyànjú láti jí mi",JÍ,AWAKE "Apá ọ̀tún ni ilé mi wà, ní agbègbè ojuelegba",Apá,Hand Mo féràn láti máa fi ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀ jẹ́ ẹ̀kọ,TẸ̀TẸ̀,A VARIETY OF VEGETABLE Jẹ́jẹ́ ni òjò to rọ lana rọ̀,Jẹ́jẹ́,Gently "Èmi pẹ̀lú olùkọ́ èdè Yorùbá, awo ni wá",AWO,SECRET Irú bàtà wo ní o fẹ́ rà ní ọjà,Irú,type ẸYÁ tí Ẹ̀gbọ́n mi fi ń dá ẹmu tí sọnù,ẸYÁ,TEAR Mo ra bàtà ní ọjà lánàá,Bàtà,Shoe "ORÍ lẹja fí n labú,ORÍ ni akàn n fí lalẹ lódò",ORÍ, Àṣà Yorùbá wuyì púpọ̀ láwùjọ àwọn àṣà tí ó kù,ÀṢÀ,CULTURE Ọsẹ akọkọ ni oṣù keji odun yii ni ọjọ ìbí mi,Ọsẹ,Week Ọmọdé gbọdọ b'ọ̀wọ̀ fún ẹni tó jùú lọ,Ọ̀wọ̀,honour Pakute bàbá ọdẹ tí pa ọ̀yà,Ọ̀YÀ,GRASS CUTTER "Mo fẹràn ọkọ mi púpọ̀,mi o le fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ seré",Ọkọ,husband Òjìji Olatunde ń dẹru bàá,ÒJÌJI,SHADOW Owó ti a ná níbi ìgbéyàwó náà kò kéré,Owó,money Kòsí ẹni tí ọ mọ bi ọlẹ̀ se n dénú alaboyun,Ọlẹ̀,Foetus Ìfé ni a fi wa ara wa rí nínú igbó Olugbade,ÌFÉ,WHISTLING Oyebisi kò fi ìyè sí ohun tí olùkọ́ rẹ̀ ń kọ́ ọ,IYÈ,MIND Ìlú Òró ni a ti ní ṣíṣe lọla,ÒRÓ,"A CITY IN KWARA STATE, NIGERIA" Kúnlè sọ ọ̀rẹ́ rẹ̀ ní ìgbò ni imú ni ẹ̀jẹ̀ bá yọ ni imu rẹ̀,Ìgbò,headbutt "Bámi rántí sọ fún ìyá Dosumu pé, mo nílò àdá méjì",ÀDÁ,CUTLASS ògun aràn tun ti gb'owo lori,Aràn,worm Ọdẹ náà pa ERÈ l'oko,Erè,Snake (python) Igbó ti kún bo ile baba àgbà,Igbó,Bush ẸTÙ méjì ni a ní nílé tí a ń sìn,ẸTÙ,GUINEA FOWL Ìwọ́ we mọ ọmọ náà lọrùn nigbati ìyá rẹ̀ bí I,Ìwọ́,Umbilical cord Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ sí ilé olùkọ́ lati pọn omi sùgbọ́n wọn ò mú igbá lọ́wọ́,Igbá,fetcher Ri dájú pé o ra ògùn fún ikun tí o mu ọ,Ikun,Mucus Ilà kẹkẹ dára ní ẹ̀kẹ́ Yéwándé gidigidi,KẸ́KẸ́,A PECULIAR FACIAL MARK Olukọ ní kí ọmọ ile-iwe kọọkan mu ọwọ̀ kọọkan wa,Ọwọ̀,Broom Awọn ọmọ ogun oril'ede yìí ṣetán láti bá àwọn agbesunmomi jagun,Jagun,To make war "Taani òye ayé yìí yé, kí ó wá sọ",AYÉ,EARTH ìyá ra bàtà tuntun fún ọmọ rẹ̀,Bàtà,Shoe Ọwọ́ àwọn agbofinró tẹ ọkùnrin tó n ta igbó,Igbó,India helm "Pátákò Ẹfọ̀n, kakaka lo má ń ta ajá lẹ́nu",PÁTÁKÒ,HOOF Àwọn Ikán yìí nílò àmójútó gidigidi,IKÁN,TERMITE Ọbẹ̀ ilá pẹlú gbegiri a máa dùn lórí amala,Ilá,Okro Ní bo ìyá ìkókó gbà lọ,ÌKÓKÓ,BABY Ìná àpà ni Kúnlè ná fún olorin,Ìná,spent Ìlú Adà ni ìyá Rọlakẹ ti bẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀,ADÀ,"A TOWN IN OSUN STATE, NIGERIA" Bàbá mí ra ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ní àná,Ọkọ̀,CAR Ó ní láti gbọ́n epo ra ojú Ówo náà kí ó lè tètè dẹ̀,ÓWO,BOIL Ọ̀gà inú ayanran mi ti sá lọ,Ọ̀GÀ,CHAMELEON Ọ̀dẹ̀ ni gbogbo wa yóò jókòó sí lónìí,Ọ̀DẸ̀,PASSAGE Solape ń gbìyànjú láti gba ilé-ìtajà sí bẹrẹ,BẸRẸ,"AN AREA IN IBADAN, OYO STATE" Ma se sọ ọ̀rọ̀ òdì sí ọmọ ẹní Kejì rẹ,Òdì,other side of something Ọmọ náà jẹun sí ikùn tí o sì yó,Ikùn,Stomach Bàbá Atinukẹ ní oko ńlá mẹ́ta tí ó fi gbin ikàn,IKÀN,GARDEN EGG Ìgbò ni Ṣọla fi má n bori awọn alátakọ̀ rẹ̀ nígbà tí ìjà bá wáyé-,Ìgbò,headbutt "Ti igbó ba pọ̀ ní àyíká, o le ṣe òkùnfà ẹ̀fọn",Igbó,Bush Awò ni àwọn dókítà fún Olabisi tí sọnù,AWÒ,SPECTACLE Iyè ọmọ náà ti ra pẹ̀lú ibẹru,IYÈ,MIND lọ ká ìtẹ́ tí o fi sún,Ìtẹ́,Mat Bí a múra sí iṣẹ ọwọ ẹni oseese kìí ìṣẹ́ jìnà sí ni,Ìṣẹ́,poverty Iwe adìẹ náà kún mi lẹ́nu púpọ̀,IWE,GIZZARD Ọgbọ̀n ọjọ́ ni o wà nínú osù kẹrin,Ọgbọ̀n,Thirty "Àsá tí ó gbémi ni adìẹ, kò ní pẹ́ bá ọlọ́jọ́ pàdé",ÀSÁ,EAGLE Ìlà ti adari ayo fa silẹ ni agbaboolu naa fi'binu parẹ́ ti o fi gba kaadi pupa,Ìlà,line Ìkòkò ìyá àgbà tí fọ́ yángá-yángá,ÌKÒKÒ,LOCAL POT Ọmọ bíbí ìlú Ọ̀wọ̀ ni Gomina ipinlẹ Òndó àná,Ọ̀wọ̀,A town in Ondo State Olùkọ́ àgbà fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní owó láti fi ra oúnjẹ,Owó,money jagunjagun náà fí ọ̀kọ̀ gba ara rẹ̀ lẹ ní ojú Ogun,Ọ̀kọ̀,spare Ìlú Awó kò jìnnà sí ìlú Gómìnà,AWÓ,A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA Ègbo díẹ̀ àti ẹ̀wà díẹ̀ ti tó fún un èmi,ÈGBO,FOOD DERIVED FROM MAIZE Ogun jalumi kìí se tí ènìyàn lè gbàgbé,OGUN,WAR "Lẹ́yìn tí a fi ẹ̀fọ́ tẹ̀tẹ̀ jẹ iyán tán, bàbá àgbá pa aalọ fún un wa",TẸ̀TẸ̀,A VARIETY OF VEGETABLE Pátákó ajúwe lo jẹ́ atọ́na láti dé ilé ìjọsìn naa,PÁTÁKÓ,"PLANT, BOARD" Owó àjọ máa ń bo ènìyàn ní àṣírí púpọ̀,ÀJỌ,CONTRIBUTION "Fọlákẹ́ fi ogún ẹgbẹ̀rún s'owo, o sí jẹ èrè ẹgbẹrun máàrún",Èrè,Gain/Profit Ìsín ni ó pọ̀ jù ni odò adágún inú oko mi,ÌSÍN,SMALL CATFISH Eré ni Ṣọla ati Dayọ nṣe ki o tó d'ija,Eré,Play/Drama Ishola rí owó ribiribi níbi ọkà oko rẹ̀ ni ọdún yìí,ỌKÀ,GUINEA CORN Ohun amohunmaworan rẹ ni lọ sókè ju,Ohùn,Sound Àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ yóò yọjú sì Kábíyèsí ní òṣùpá mẹta tó ń bọ̀,Ẹ̀SÌN,RELIGION Ọmọ náà ni ọ̀wọ́ lẹyìn,Ọ̀wọ́,Group/ Collectively eegún tí yóò erin kò sí nígbó,Eegún,masqurade Bí ajá bá rí olówó Re yíò ju ìrù sí,Ìrù,tail Awọn olè se ọkùnrin naa ni osẹ́ púpọ̀,Ọsẹ́,injury Irọ̀ ni èmi àti Adeyọde,IRỌ̀,AGE MATE "Àgbà kì í wà lọ́jà, kí orí ọmọ tuntun kó wọ́",ÀGBÀ,ELDERLY PERSON wakati meji ni ọkọ ayọkẹlẹ yóò lo lọnà láti ìlú ìlá sí ìlú Osogbo,Ìlá,a town in Osun state Ará kannáà ni ìran ìbíní àti yorùbá jẹ́,Ará,related people Orí òró ni àwọn òní janduku pa ọkùnrin náà sí,ÒRÓ,STAND ìyàwó tí ọkọ fẹràn jù lo ń se ọbẹ̀ fún ọkọ,Ọkọ,husband Ìlú Ìbàdàn ni àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ ní òpin ọ̀sẹ̀,Ìlú,Village "Bí obìnrin bá fi ojú di orò, yóò dá ara rẹ̀ ni ẹ̀bi",ORÒ,A god in Yoruba land